Èdè Balanta
Balanta (tàbí Balant) jẹ́ àwọn èdè Bak méjì tí ó jọra tí àwọn ènìyàn Balanta ń sọ.
Balanta | |
---|---|
Sísọ ní | (Balanta-Kentohe) Guinea-Bissau, (Balanta-Ganja) the Gambia, Senegal |
Ọjọ́ ìdásílẹ̀ | 2006 |
Ẹ̀yà | Balanta |
Ìye àwọn afisọ̀rọ̀ | 510,000 |
Èdè ìbátan | Niger-Kóngò
|
Èdè ajẹ́kékeré ní | Senegal |
Àwọn àmìọ̀rọ̀ èdè | |
ISO 639-3 | either: ble – Balanta-Kentohe bjt – Balanta-Ganja |
Àlàyé
àtúnṣeÀ le pín èdè Balanta sí méjì: Balanta-Kentohe àti Balanta-Ganja.[1][2]
Balanta-Kentohe
àtúnṣeÀwọn ènìyàn tí ó tó 423,000 ní iye ni ó ń sọ èdè Balanta-Kentohe (Kəntɔhɛ) ní orílè-èdè Guinea-Bissau (ní ọdún 2006, àwọn tí ó ń sọ èdè náà tó 397,000, ọ̀pọ̀lọpọ̀ wọn sì ló wà ní Agbègbè Oio[3]) àti ní Gámbíà. Wọ́n ti ṣàgbéjáde àwọn fíìmù àti àwọn apá Bíbélì kan ní èdè Balanta-Kentohe.
The Kəntɔhɛ dialect is spoken in the north, while the Fora dialect is spoken in the south.[4]
Ethnologue lists the alternative names of Balanta-Kentohe as Alante, Balanda, Balant, Balanta, Balante, Ballante, Belante, Brassa, Bulanda, Frase, Fora, Kantohe (Kentohe, Queuthoe), Naga and Mane. The Naga, Mane and Kantohe dialects may be separate languages.
Balanta-Ganja
àtúnṣeÀwọn tí ó sọ èdè Balanta-Ganja ní gúúsù àti gúúsù ìwọ oòrùn Senegal tó 86,000 ní iye (ní ọdún 2006). is less than 1% for Balanta-Ganja.[1][2]
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ 1.0 1.1 "Balanta-Kentohe". Ethnologue (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-01-06.
- ↑ 2.0 2.1 "Balanta-Ganja". Ethnologue (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-01-06.
- ↑ "Balanta-Kentohe Language (ble)". The Rosetta Project. Archived from the original on 2011-07-27. Retrieved 2011-02-28.
- ↑ Wilson, William A. A. (2007) (in en). Guinea Languages of the Atlantic Group: Description and Internal Classification. Schriften zur Afrikanistik, 12. Frankfurt am Main: Peter Lang.