Sẹ̀nẹ̀gàl (Faransé: le Sénégal) tabi Orile-ede Olominira ile Senegal je orile-ede ni Iwoorun Afrika. Senegal ni Okun Atlantiki ni iwoorun, Mauritania ni ariwa, Mali ni ilaorun, ati Guinea ati Guinea-Bissau ni guusu. Sinu die lo ku ko yipo Gambia ka patapata si ariwa, ilaorun ati guusu, ibi to se ku nikan ni eti okun Atlanti Gambia[4] Ifesi ile Senegal fe to 197,000 km², be si ni o ni onibugbe bi 13.7 legbegberun.

Orílẹ̀-èdè Olómìnira ilẹ̀ Sẹ̀nẹ̀gàl
République du Sénégal
Motto: "Un Peuple, Un But, Une Foi"  (French)
"One People, One Goal, One Faith"
Location of Sẹ̀nẹ̀gàl
Olùìlú
àti ìlú tótóbijùlọ
Dakar
Àwọn èdè ìṣẹ́ọbaFrench
Lílò regional languagesWolof, Soninke, Seereer-Siin, Fula, Maninka, Diola,[1]
Orúkọ aráàlúSenegalese
ÌjọbaSemi-presidential republic
• President
Macky Sall
Sidiki Kaba
Independence
• from France
4 April 1960
Ìtóbi
• Total
196,723 km2 (75,955 sq mi) (87th)
• Omi (%)
2.1
Alábùgbé
• 2009 estimate
12,534,000[2] (72nd)
• Ìdìmọ́ra
63.7/km2 (165.0/sq mi) (137th)
GDP (PPP)2008 estimate
• Total
$21.773 billion[3]
• Per capita
$1,739[3]
GDP (nominal)2008 estimate
• Total
$13.350 billion[3]
• Per capita
$1,066[3]
Gini (1995)41.3
medium
HDI (2007)0.464
Error: Invalid HDI value · 166th
OwónínáCFA franc (XOF)
Ibi àkókòUTC
Ojúọ̀nà ọkọ́right
Àmì tẹlifóònù221
Internet TLD.sn

Dakar ni oluilu re to wa lori Cap-Vert Peninsula ni eti Okun Atlantiki. Bi iye ida kan ninu meta awon ara Senegal ni won n gbe labe ila aini kakiriaye to je US$ 1.25 lojumo.[5]



Itokasi àtúnṣe

  1. « La langue officielle de la République du Sénégal est le Français. Les langues nationales sont le Diola, le Malinké, le Pulaar, le Sérère, le Soninké, le Wolof et toute autre langue nationale qui sera codifiée. » − Extrait du site officiel du gouvernement sénégalais Archived 2006-07-25 at the Wayback Machine.
  2. Department of Economic and Social Affairs Population Division (2009) (.PDF). World Population Prospects, Table A.1. 2008 revision. United Nations. http://www.un.org/esa/population/publications/wpp2008/wpp2008_text_tables.pdf. Retrieved 2009-03-12. 
  3. 3.0 3.1 3.2 3.3 "Senegal". International Monetary Fund. Retrieved 2009-10-01. 
  4. Gambia lies almost entirely within Senegal, surrounded by it on the north, east and south; from its western coast, Gambia's territory follows the Gambia River more than 300 kilometres (186 miles) inland.
  5. Human Development Indices, Table 3: Human and income poverty, p. 35. Retrieved on 1 June 2009