Èdè Bàlóṣì
(Àtúnjúwe láti Èdè Baloṣi)
Ọmọ ẹgbẹ́ èdè tí a ń pé ní Iranian ni Bàlúṣì. Àwọn tí ó ń sọ ọ́ tọ́ mílíọ̀nù márùn-ún. Púpọ̀ nínú àwọn tí ó ń sọ ọ́ yìí ni ó wà ní Pakísítáánì (Pakistan) ní Bàlúṣísítáànì (Baluchistan). Baluclistan yìí ni ìpínlẹ̀ (province) tí ó wà ní apá ìwọ̀-oòrùn jùní pakcstan. Àwọn tí ó ń sọ èdè yìí ní Baluchistan tó mílíọ̀nù (Iran), Afuganíísítáànù (Afghanistan) àti In-índíà (India). Àkọtọ́ Lárúbáwá (Arabic) ni wọ́n fi kọ ọ́ sílẹ̀. Àjọ kan wà tí wọ́n ń pè ní Baluchi Academy tí ó ń ń sí pé àkọsílẹ̀ èdè yìí páye. [1] [2]
Balochi | ||||||
---|---|---|---|---|---|---|
بلوچی baločî | ||||||
[[File:|border|200px]] | ||||||
Sísọ ní | Pakistan, Iran, Afghanistan, Turkmenistan, UAE, Oman | |||||
Ìye àwọn afisọ̀rọ̀ | 7–8 million (1998, Ethnologue) not include Northern Balochi | |||||
Èdè ìbátan | ||||||
Lílò bíi oníbiṣẹ́ | ||||||
Àkóso lọ́wọ́ | Kòsí àkóso oníbiṣẹ́ | |||||
Àwọn àmìọ̀rọ̀ èdè | ||||||
ISO 639-2 | bal | |||||
ISO 639-3 | variously: bal – Baluchi (generic) bgp – Eastern Balochi bgn – Western Balochi bcc – Southern Balochi | |||||
|
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Baluchi language, alphabet and pronunciation". Omniglot. 2019-06-16. Retrieved 2019-11-20.
- ↑ "The Balochi Language Project - Uppsala universitet". Institutionen för lingvistik och filologi. 2019-11-15. Archived from the original on 2019-08-25. Retrieved 2019-11-20.