Èdè Bijago
Èdè Bijago tabi Bidyogo jẹ́ ọkan pàtàkì lára àwọn orisìírísìí èdè bí i mẹ́ẹ́dógbọ̀n tí wọ́n ń sọ láti ilẹ Guinea-Bissau, orúkọ mìíràn tí a tún mọ èdè yìí sí ni: Bigogo, Byougout. Bijuga, Budjago, Bugago. Bákan náà ni a mò wọ́n mọ àwọn. Ẹ̀ka Èdè bíi: Anhaki, kagbaaga, Kajoko, Kamọna àti Orango wọ́pọ̀ nínú èdè Bidgogo.
Bijago | |
---|---|
Sísọ ní | Guinea-Bissau |
Agbègbè | Offshore Bissagos Islands |
Ìye àwọn afisọ̀rọ̀ | 30,000 |
Èdè ìbátan | Niger-Kóngò
|
Àwọn àmìọ̀rọ̀ èdè | |
ISO 639-3 | bjg |
Gbogbo àwọn èdè náà ni wọn sì tì ń sọ títí di àkókò yìí. Àwọn Niger-Congo tó jẹ́ ẹya Bijago ló máa ń ṣọ èdè náà.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |