Èdè Spéìn

(Àtúnjúwe láti Èdè Híspánì)

Èdè Sípéènì (español tàbí castellano) jẹ́ èdè ní orílẹ̀-èdè Sípéènì, wọ́n sì sọ èdè yìí púpọ̀ ní àwọn orílẹ̀-èdè Apá Gúúsu Amẹ́ríkà. Èdè Sípéènì jẹ́ ọ̀kan lára àwọn èdè Rómáńsì, àwọn èyí tí wọ́n fà yọ láti inú èdè Látìnì.

Èdè Sípéènì
español, castellano
Ìpè/espaˈɲol/, /kast̪eˈʎano/
Sísọ ní(see below)
Ìye àwọn afisọ̀rọ̀First languagea: 500 million
a as second and first language 600 million. All numbers are approximate.
Èdè ìbátan
Sístẹ́mù ìkọLatin (Spanish variant)
Lílò bíi oníbiṣẹ́
Èdè oníbiṣẹ́ ní21 countries, United Nations, European Union, Organization of American States, Organization of Ibero-American States, African Union, Latin Union, Caricom, North American Free Trade Agreement, Antarctic Treaty.
Àkóso lọ́wọ́Association of Spanish Language Academies (Real Academia Española and 21 other national Spanish language academies)
Àwọn àmìọ̀rọ̀ èdè
ISO 639-1es
ISO 639-2spa
ISO 639-3spa