Èdè Tem
Tem, tàbí Kotokoli (Cotocoli), jẹ́ ọ̀kan lára àwọn èdè Gur tí wọ́n ń sọ ní Togo, Ghana, Benin àti Burkina Faso. Ó tún jẹ́ èdè tí àwọn kọ̀kan ní àyíká orílẹ̀ èdè yí ń sọ. Ní Ghana, àwọn ènìyàn Kotokoli wá láti àríwá agbègbè Volta ní ìlú kan tí wọ́n ń pè ní Koue. Koue pín àlà pẹ̀lú Togo, odò kékeré(odò Koue) sì ló wà láàrin Koue àti Togo.
Tem | |
---|---|
Kotokoli | |
Sísọ ní | Togo, Ghana, Benin, Burkina Faso |
Ọjọ́ ìdásílẹ̀ | 2012–2018 |
Ẹ̀yà | Tem people |
Ìye àwọn afisọ̀rọ̀ | Àdàkọ:Sigfig |
Èdè ìbátan | |
Sístẹ́mù ìkọ | Latin (Tem alphabet) Tem Braille Arabic (former) |
Èdè ajẹ́kékeré ní | Benin |
Àwọn àmìọ̀rọ̀ èdè | |
ISO 639-3 | kdh |
Yàtò sí ilè abínibí wọn, àwọn Tem/Kotokoli yapa káàkiri àwọn ibi ní orílẹ̀-èdè Ghana. Wọ́n pọ̀ ní àwọn agbègbè bi Nima-Mamobi, Madina, Dodowa, Asaman, Jamasi, Aboaso àti àwọn agbègbè míràn. Orúkọ olóyè wọn ní Wuro, òun sì ni olórí ilẹ̀ Koue.
Álífábẹ́tì wọn
àtúnṣeÁlífábẹ́tì | ||||||||||||||||||||||||||||||||||
---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|
Uppercase | A | B | C | D | Ɖ | E | Ɛ | F | G | Gb | H | I | Ɩ | J | K | Kp | L | M | N | Ny | Ŋ | Ŋm | O | Ɔ | P | R | S | T | U | Ʊ | V | W | Y | Z |
Lowercase | a | b | c | d | ɖ | e | ɛ | f | g | gb | h | i | ɩ | j | k | kp | l | m | n | ny | ŋ | ŋm | o | ɔ | p | r | s | t | u | ʊ | v | w | y | z |