Èkó (tàbí Lagos ní èdè Gẹ̀ẹ́sì /ˈlɡɒs/, US also /ˈlɑːɡs/;[3] Yorùbá: Èkó) ni ìlú tó ní èrò tó pọ̀ jùlọ ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà àti ní gbogbo ilẹ̀ Áfríkà.[4][5] Èkó jẹ́ ilé-ajé pàtàkì ní gbogbo Áfríkà àti oríta òkòwò ní Ìpínlẹ̀ Èkó. Èkó gẹ́gẹ́bí ìlú-nínlá ni o ní GDP kẹrin tó pọ̀jùlọ ní Áfríkà,[6][7] ibẹ̀ sì ni èbúté ọkọ̀-ojúomi tó tó bijùlọ àti tó láápọn jùlọ ní ilẹ̀ Áfríkà.[8][9][10] Èkó ni ìkan láàrin àwọn ìlú tí ó ún ní ìgbèdàgbà kíákíá jùlọ ní àgbáyé.[18]

Lagos

Èkó
LagosNg222.jpg
Flag of Lagos
Flag
Official seal of Lagos
Seal
Map of Lagos Metropolis
Map of Lagos Metropolis
Country Nigeria
StateLagos State
LGALagos Island
Area
 • Urban
999.6 km2 (385.9 sq mi)
Population
 (2006 census, preliminary)
 • Density7,941/km2 (20,569.9/sq mi)
 • Urban
7,937,932
Time zoneUTC+1 (CET)
Websitehttp://www.lagosstate.gov.ng/

Èkó ní orúkọ tí àwọn Yorùbá npè ìlú erékùsù ti o ti di olú ìlú àti ibùjoko ìjoba gbogbo-gbòò fún ilè Nàìjíríà ní ojó òní. Ìlú Yorùbá ní, ṣugbọ́n orúkọ ti àwọn ènìà àgbáíyé fi npè é ni èyí ti àwọn Òyìnbó Potogi tí o kọ́ bẹ etíkun ilẹ̀ Yorùbá wò fún un. Orúkọ náà ni “Lagos”, eyi ti ìtumọ rẹ̀ jásí “adágún” tàbí “ọ̀sà”, nitoripe ọ̀sà ni o yi ìlú náà ka...

Àwọn Ẹ̀yà Yorùbá ti Àwórì ni o kọ́kọ́ tẹ̀dó si agbègbè Ìlú Èkó, lábé ìsàkóso àti Ìtọnà olórí-i won, Ọ̀lọ̀fin, àwọn Àwórì kọ́kọ́ tẹ̀dó sí erékùsù Ìddó, Léyìn ìgbà náà ni won bẹ̀rẹ̀ si ní wọnú-u àwọn agbègbè yókù Èkó láti tẹ̀dó. Ní séntúrì k'àrùn din l'ógún {15th Century}, Ìlú Èkó, bo si abẹ́ ìsàkóso Ìjoba Bini. Ìgbà náà ni àwọn Ológun Ìlú náà so agbègbè ìlú náà ní Èkó, eleyii, tí o túmò si [Ibi tí àwọn Ológun ti n simi} Ní èdè Edo/Bini. Gbogbo eleyii sele labe olórí àwọn Bini ni ìgbà náà Ọba Ọ̀rọ̀gbà. Léyìn ti èyí sele,nii Ìjọba Bìní fi Baale jẹ́ oyè, láti máà M'ójútó/Se Àkóso, àti Gbígbà Ìsákọ́lè {Tribute} ìlú náà bii agbègbè lábé-fé Ìjọba ńlá ti Bìní. Ọba Yorùbá akoko ti Ìlú Èkó jẹ́, ní Ọba Aṣípa. Ní ọdun-ún 1472, àwọn Òyìnbó Pọ́tókì{Portuguese} dé si ilè Èkó, àwọn Pọ́tókì náà ní Òyìnbó àkókó, tí o máà de Ilè -Èkó láti Erékùsù Orílè-ẹ̀dẹ̀ Yuropu ní ìgbà náà.

ÀwòránÀtúnṣe

Ìtọ́kasíÀtúnṣe

 1. Summing the 16 LGAs making up Metropolitan Lagos (Agége, Ajéròmí-Ìfélódùn, Àlímòshọ́, Àmùwó-Ọ̀dọ̀fin, Àpápá, Etí-Ọ̀sà, Ìfàkò-Ìjàìyè, Ìkejà, Kòsòfẹ́, Lagos Island, Lagos Mainland, Mushin, Ọ̀jọ́, Oshòdì-Ìsolò, Shómólú, Surulérè) as per:
  The Nigeria Congress. "Administrative Levels - Lagos State". Retrieved 2007-06-29. 
 2. Summing the 16 LGAs making up Metropolitan Lagos (Agége, Ajéròmí-Ìfélódùn, Àlímòshọ́, Àmùwó-Ọ̀dọ̀fin, Àpápá, Etí-Ọ̀sà, Ìfàkò-Ìjàìyè, Ìkejà, Kòsòfẹ́, Lagos Island, Lagos Mainland, Mushin, Ojo, Oshodi-Isolo, Shomolu, Surulere) as per:
  Federal Republic of Nigeria Official Gazette (15 May 2007). "Legal Notice on Publication of the Details of the Breakdown of the National and State Provisional Totals 2006 Census" (PDF). Retrieved 2007-06-29. 
 3. Àdàkọ:Cite EPD
 4. "What Makes Lagos a Model City". New York Times. 7 January 2014. https://www.nytimes.com/2014/01/08/opinion/what-makes-lagos-a-model-city.html?_r=0. Retrieved 16 March 2015. 
 5. John Campbell (10 July 2012). "This Is Africa's New Biggest City: Lagos, Nigeria, Population 21 Million". The Atlantic (Washington DC). https://www.theatlantic.com/international/archive/2012/07/this-is-africas-new-biggest-city-lagos-nigeria-population-25-million/259611/. Retrieved 23 September 2012. 
 6. "These cities are the hubs of Africa’s economic boom". Big Think (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2018-10-04. Retrieved 2019-04-23. 
 7. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named metropolitan Lagos
 8. "Africa's biggest shipping ports". Businesstech. 8 March 2015. Retrieved 26 October 2015. 
 9. Brian Rajewski (1998). Africa, Volume 1 of Cities of the World: a compilation of current information on cultural, geographical, and political conditions in the countries and cities of six continents, based on the Department of State's "post reports". Gale Research International, Limited. ISBN 978-0-810-3769-22. https://books.google.com/books?id=E-VwMKQlGjIC. 
 10. Loretta Lees; Hyun Bang Shin; Ernesto López Morales (2015). Global Gentrifications: Uneven Development and Displacement. Policy Press. p. 315. ISBN 978-1-447-3134-89. https://books.google.com/books?id=Lzt7BgAAQBAJ&pg=PA315&dq=. 
 11. African Cities Driving the NEPAD Initiative. 2006. p. 202. ISBN 978-9-211318159. https://books.google.com/books?id=tk5TP7bsXnkC&pg=PA202&dq=. 
 12. John Hartley; Jason Potts; Terry Flew; Stuart Cunningham; Michael Keane; John Banks (2012). Key Concepts in Creative Industries. SAGE. p. 47. ISBN 978-1-446-2028-90. https://books.google.com/books?id=sMnj88kYVmcC&pg=PT60&dq=. 
 13. Helmut K Anheier; Yudhishthir Raj Isar (2012). Cultures and Globalization: Cities, Cultural Policy and Governance. SAGE. p. 118. ISBN 978-1-446-2585-07. https://books.google.com/books?id=wQJb1QpZz_4C&pg=PA118&dq=. 
 14. Stuart Cunningham (2013). Hidden Innovation: Policy, Industry and the Creative Sector (Creative Economy and Innovation Culture Se Series). Univ. of Queensland Press. p. 163. ISBN 978-0-702-2509-89. https://books.google.com/books?id=oy-de29AtvYC&pg=PA163. 
 15. Lisa Benton-Short; John Rennie Short (2013). Cities and Nature. Routledge Critical Introductions to Urbanism and the City. p. 7. ISBN 978-1-134252749. https://books.google.com/books?id=rQ_ZLuqZT54C&pg=PA71&dq=. 
 16. Kerstin Pinther; Larissa Förster; Christian Hanussek (2012). "Afropolis: City Media Art". Jacana Media. p. 18. ISBN 978-1-431-4032-57. 
 17. Salif Diop; Jean-Paul Barusseau; Cyr Descamps (2014). The Land/Ocean Interactions in the Coastal Zone of West and Central Africa Estuaries of the World. Springer. p. 66. ISBN 978-3-319-0638-81. https://books.google.com/books?id=8JPIAwAAQBAJ&pg=PA66&dq=. 
 18. Sources: [11][12][13][14][15][16][17]
 • J.F. Odunjo (1969), ÌLÚ ÈKÓ ATI ÌJÈBÚ, Isẹ́ Àtúnyèwò ẹ̀kọ́ nipa ọ̀rọ̀ gbígbàsọ Ojú-ìwé 49-54, Èkó Ìjìnlẹ̀ Yorùbá Alawiye, Fún Àwọn Ilé Ẹ̀kó Gíga, Apá Kejì, Longmans of Nigeria.

Ìtọ́kasí ÀrèÀtúnṣe