Ìfé ni lílo ṣíṣu ẹnu pọ̀ roboto láti lè jẹ́ kí afẹfẹ́ tàbí èémí tí ó ń bọ̀ láti káà ọ̀fun ó ráyè gbà kọjá, tabi kí á fa afẹ́fẹ́ láti ìta wọ inú ẹ ẹnu kí ó lè mú ìró kan tàbí òmíràn tí a fẹ́ jáde láì lo fèrè. Èémí tàbí afẹ́fẹ́ tí a fà tàbí fẹ́ yí ni ètè tàbí ahọ́n ma ń darí ré kí ó lè mú ìró tí bá fẹ́ jáde. [1].

The Whistling Boy, Frank Duveneck (1872)

Àwon Ìtókasí

àtúnṣe
  1. "How to Whistle With Your Fingers". The Art of Manliness. April 8, 2012. Retrieved March 7, 2017.