Ìfagbáramẹ́rindìmú (Kẹ́místrì)
Nínú kẹ́místrì, ìfagbáramẹ́rindìmú ni ipo atomu kan to ni with four elektronu merin ti won wa fun isopo kemika ajofagbadimu ni ibi idimu re (igba elektronu to bosodejulo). Apere kan je methani (CH4): atomu the tetravalent kárbọ̀nù afagbaramerindimu se isopo ajofagbaradimu pelu àwon atomu hydrogen merin. Atomu karbonu yi unje afagbaramerindimu (tetravalent) nitoripe o se isopo ajofagbaradimu 4.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |