Ìlù Bàtá
Ìlù Bàtà jẹ ìlù kan ti o ni oju meji, ikan ni iwaju ikan lẹyin. Amọ, oju ilu ti o wa ni iwaju fẹ̀ ju ti ẹ̀yìn lọ. Ọdun ibilẹ, ọdun òrìṣà Sàngó, ilu Santería ní Cuba láti ọdún 1800s, àti ní Puerto Rico àti ni orílẹ̀-èdè Amẹríka láti ọdun 1950s.[1] ni a ma n lo ilu yi fun, bakan naa ni wọn tun ma n loo fun oriṣriṣi ayẹyẹ ni ile Yorùbá.
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ Corrales, Mark (July 28, 2004). "The Bata Drums". Reprinted by World Music Central. Original article published by the Latin American Folk Institute (LAFI) of Washington DC. Archived from the original on 30 January 2021. Retrieved January 10, 2022. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help)