Ìròyìn Oṣù Kẹfà 2012
- Mohamed Morsi 'jẹ́ dídìbòyàn sí ipò Ààrẹ ilẹ̀ Ẹ́gíptì.
- Nínú bọ́ọ́lù-alápẹ̀rẹ̀, Miami Heat borí Oklahoma City Thunder láti gba ife-ìdíje NBA.
- Ààrẹ ilẹ̀ Paragúáì Fernando Lugo (àwòrán) jẹ́ yíyokúrò lórí àga, ó sì jẹ́ rírọ́pò pẹ̀lú Federico Franco.
- Bàálù akóèrò jálu ilé ní Èkó, ní Nàìjíríà, gbogbo àwọn èrò 153 inú rẹ̀ lókú.