Ìyá
Ìyá (màmá tabi mọ̀nmọ́n) ni òbí tó jẹ́ obìnrin èèyàn kan. Ìyá àti bàbá jẹ́ òbí fún ọmọ tàbí ènìyàn kan. Ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ Ìgbà, ìyá ló máa ń bí ọmọ fún ara rẹ̀, nígbà mìíràn ó lè gba ọmọ ẹlòmíràn bí ọmọ rẹ̀ tàbí kí ó gba ọmọ ẹlòmíràn tọ́.[1] [2]

Ìyá àti ọmọ rẹ̀
Àwọn Ìtọ́kasíÀtúnṣe
- ↑ "MOTHER - meaning in the Cambridge English Dictionary". Google. Retrieved 2020-01-10.
- ↑ "Mother". Lexico Dictionaries | English. Retrieved 2020-01-10.