Àdàkọ:Use Nigerian English

Folake Aremu
Ọjọ́ìbí(1960-10-10)10 Oṣù Kẹ̀wá 1960
Olla, Kwara State
Aláìsí5 January 2021(2021-01-05) (ọmọ ọdún 60)
Ibadan, Oyo State
Orílẹ̀-èdèNigerian
Orúkọ mírànOrisabunmi
Iṣẹ́Actress
Ìgbà iṣẹ́1980s–2021

Fọlákẹ́ Àrẹ̀mú tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí Òrìṣábùnmi, (tí wọ́n bí lọ́jọ́ kẹwàá oṣù kẹwàá ọdún 1960 [1], tí ó sìn kú lọ́jọ́ kẹfà oṣù kìíní ọdún 2021) [2] jẹ́ gbajúmọ̀ Òṣèré-bìnrin sinimá àgbéléwò àti eléré orí ìtàgé ọmọ bíbí Ìpínlẹ̀ Kwara lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Ó jẹ́ oṣèré-bìnrin tí ó sáàbà máa ń kópa ìyá-òòṣà, apẹ̀tùsáwọ̀ tàbí aṣètùtù ìlú, àjẹ́ funfun tàbí àjẹ́ aṣoore nínú sinimá.[3] Aremu is considered one of Yoruba's most talented actresses.[4] Wọ́n yàn án fún àmì-ẹ̀yẹ òṣèré tí wọ́n wádìí nípa rẹ̀ jùlọ lẹ́yìn ikú ni ibi ayẹyẹ àmì-ẹ̀yẹ NET HONOURS lọ́dún 2021.[5] Ó kú lọ́jọ́ karùn-ún oṣù kìíní ọdún 2021 nílé rẹ̀ ní Ìbàdàn.[6][7]

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. Samuel, Mofijesusewa (2020-12-28). "Orisabunmi: Everything You Need To Know About The Good Witch Of Yoruba Film.". Nigerian Entertainment Today. Retrieved 2021-01-10. 
  2. "Veteran Yoruba actress, Orisabunmi, is dead". Premium Times Nigeria. 2021-01-06. Retrieved 2021-01-10. 
  3. "Nollywood stars who died in January 2021 - P.M. News" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-10-06. 
  4. Augoye, Jayne (2021-01-06). "Veteran Yoruba actress, Orisabunmi, is dead". Premium Times Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-10-06. 
  5. Orodare, Michael (2021-06-20). "NET Honours: Orisabunmi Wins Posthumous award - ‘Most Searched Actress’". Nigerian Entertainment Today (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-10-06. 
  6. "Veteran yoruba actress Orisabunmi dies at 60". Punch Newspapers (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2021-01-06. Retrieved 2022-10-06. 
  7. "Remains of late veteran actress Orisabunmi laid to rest - P.M. News" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-10-06.