Ìpínlẹ̀ Kwara
Ìkan lára àwọn ìpínlẹ̀ ní orílé-èdè Nàìjíríà
(Àtúnjúwe láti Kwara State)
Ipinle Kwara State nickname: State of Harmony | ||
Location | ||
---|---|---|
![]() | ||
Statistics | ||
Governor (List) |
Abdulrahman Abdulrasaq (PDP) | |
Date Created | 27 May 1967 | |
Capital | Ilorin | |
Area | 36,825 km² Ranked 9th | |
Population 1991 Census 2005 estimate |
Ranked 31st 1,566,469 2,591,555 | |
ISO 3166-2 | NG-KW |
Kwara (Yorùbá: Ìpínlẹ̀ Kwárà) jẹ ìpínlẹ̀ ní apá ìwọ̀-oòrùn ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà. Olú-ìlú rẹ̀ ni ìlọrin. Ó wà ní àríwá àárín gbùngbùn ti a mò sí ìgbánú àárín ìlú. Yorùbá, pèlú ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn Nupe, Ìbàrìbá àti Fúlàní díẹ̀ ni wọ́n tẹ̀dó síbẹ.
Ìpínlè kwárà ní ìjoba ìpínlè mérìndilógún, ìjoba ìpínlè ti ìwò oòrùn Ìlorin ni ènìyàn tó pòjù [2]
Àwọn ìtọ́kasíÀtúnṣe
- ↑ "About Kwara State". Kwara State Government.
- ↑ "Kwara (State, Nigeria)". Population Statistics, Charts, Map and Location. 2016-03-21. Retrieved 2022-03-08.