Óscar Rafael de Jesús Arias Sánchez (ojoibi 13 September 1940) je oloselu ara orile-ede Kosta Rika to di Aare ile Kosta Rika lati odun 2006 de 2010. Teletele o tun je Aare lati 1986 de 1990 o si gba Ebun Nobel ni 1987 fun iyanju re lati mu opin ba awon ogun abele ti won nlowo nigbana ni opo awon orile-ede Aarin Amerika.

Óscar Arias
Óscar Arias.jpg
President of Costa Rica
In office
8 Ọṣù Kàrún 2006 – 8 Ọṣù Kàrún 2010
AsíwájúAbel Pacheco
Arọ́pòLaura Chinchilla
In office
8 Ọṣù Kàrún 1986 – 8 Ọṣù Kàrún 1990
AsíwájúLuis Alberto Monge
Arọ́pòRafael Ángel Calderón Fournier
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí13 Oṣù Kẹ̀sán 1940 (1940-09-13) (ọmọ ọdún 80)
Heredia, Costa Rica
Ẹgbẹ́ olóṣèlúNational Liberation Party
Alma materBoston University
University of Costa Rica
London School of Economics
University of Essex

ItokasiÀtúnṣe