Ẹ̀bùn Nobel nínú Físíksì

Ẹ̀bùn Nobel nínú Físíksì (Àdàkọ:Lang-sv) je bibun ni ekan lodun latowo Akademy àwon Sayensi Oba Swidin. O je ikan ninu Ebun Nobel marun ti won je didasile latowo akoole ijogun Alfred Nobel ni 1895 o si unje bibun lati 1901; awon yioku ni Ebun Nobel ninu Kemistri, Ebun Nobel ninu Litireso, Ebun Nobel Alafia, ati Ebun Nobel fun Iwosan. Ebun Nobel ninu Fisiksi akoko je bibun fun Wilhelm Conrad Röntgen, ara Jemani, " fun idamo ise iwofa pataki to ti se nipa iwari àwọn ìranná (tabi ìranná-x tabi x-rays)." Ebun yi unje mimojuto latowo Nobel Foundation beesini won gba kakiri bi ebun oniyijulo ti onimosayensi kan le gba ninu fisiksi. Won unfihan ni Stockholm ni bi ajoyo ododun ni 10 Osu Kejila, to je ajodun iku Nobel. Físíksì

Ẹ̀bùn Nobel nínú Físíksì
The Nobel Prize in Physics
Bíbún fún Outstanding contributions in Physics
Látọwọ́ Royal Swedish Academy of Sciences
Orílẹ̀-èdè Sweden
Bíbún láàkọ́kọ́ 1901
Ibiìtakùn oníbiṣẹ́ http://nobelprize.org
Wilhelm Röntgen (1845–1923), the first recipient of the Nobel Prize in Physics.