Ẹ̀gbá Aké
Egba Ake, tí a tún mọ̀ sí Ẹ̀gbá Aláké jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ẹ̀ka márààrún tí Ẹ̀gbá pín sí. Àwọn ẹ̀ka yòókù ni Oke-Ona, Gbagura, Owu àti Ibara (ìtàn fi yé wa pé Ibara wà lára Yewa, kì í ṣe Ẹ̀gbá, àmọ́ agbègbè Abẹ́òkúta ni ó wà báyìí. Aláké ti ìlú Ẹ̀gbá ni ọba tàbí olórí gbogbo ẹ̀yà Ẹ̀gbá.[1]
Egba Ake Egba Alake | |
---|---|
Coordinates: 7°9′39″N 3°20′54″E / 7.16083°N 3.34833°E | |
Country | Nigeria |
State | Ogun State |
Àwọn olórí
àtúnṣeÈyí ni àtòjọ àwọn olórí tàbí adarí Ẹ̀gbá, tó joyè Aláké, láti ọdún 1854[2]
Ìbèrè | Òpin | Orúkọ Olórí |
---|---|---|
1829 | 1845 | Shodeke |
1845 | 1846 | Shomoye -Regent (1st time) |
1846 | 1854 | Sagbua Okukenun -Regent |
8 Aug 1854 | 1862 | Okukenun (Sagbua Okukenun) First Alake |
1862 | 1868 | Shomoye -Regent (2nd time) |
28 Nov 1869 | 20 Dec 1877 | Ademola I |
Jan 1879 | 15 Sep 1881 | Oyekan (d. 1881) |
9 Feb 1885 | 27 Jan 1889 | Oluwajin |
18 Sep 1891 | 11 Jun 1898 | Oshokalu |
8 Aug 1898 | 28 May 1920 | Gbadebo I (1854–1920) |
27 Sep 1920 | 27 Dec 1962 | Ladapo Samuel Ademola II (1872–1962) (in exile 1948 – 3 Dec 1950) |
29 Sep 1963 | 26 Oct 1971 | Adeshina Samuel Gbadebo II (1908–1971) |
5 Aug 1972 | 3 Feb 2005 | Samuel Oyebade Mofolorunsho Lipede (1915–2005) |
24 Aug 2005 | Adedotun Aremu Gbadebo III (b. 1943)[3] |
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ Niyi Odebode (5 November 2007). "Alake, others fault Owu’s claim on Abeokuta". The Punch. Archived from the original on 5 November 2007. Retrieved 2010-09-07. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Traditional States of Nigeria". WorldStatesmen.org. Retrieved 2010-09-07.
- ↑ Niyi Odebode and Olaolu Oladipo (4 August 2005). "Gbadebo emerges new Alake – • We’re yet to confirm any candidate – Ogun govt". Online Nigeria Daily News. Archived from the original on 12 March 2012. Retrieved 3 February 2023.