Ẹ̀rọ Ìmúsáré Hádrónì Gbàngbà
Coordinates: 46°14′N 06°03′E / 46.233°N 6.050°E
LHC experiments | |
---|---|
ATLAS | A Toroidal LHC Apparatus |
CMS | Compact Muon Solenoid |
LHCb | LHC-beauty |
ALICE | A Large Ion Collider Experiment |
TOTEM | Total Cross Section, Elastic Scattering and Diffraction Dissociation |
LHCf | LHC-forward |
MoEDAL | Monopole and Exotics Detector At the LHC |
LHC preaccelerators | |
p and Pb | Linear accelerators for protons (Linac 2) and Lead (Linac 3) |
(not marked) | Proton Synchrotron Booster |
PS | Proton Synchrotron |
SPS | Super Proton Synchrotron |
Ẹ̀rọ Ìmúsáré Hádrónì Gbàngbà tabi Large Hadron Collider (LHC) ni ero imusare eruku pelu okun totobijulo ati togajulo lagbaye. Ó jẹ́ kíkọ́sókè látọwọ́ CERN láti ọdún 1998 dé 2008, pẹ̀lú èrò láti gba àwọn aṣefísíksì láyè láti ṣe àdánwò ìsọtẹ́lẹ̀ àwọn orísi àròjinlẹ̀ físíksì eruku àti físíksì olókun-gíga, àti àgàgà láti wá bọ́yá bósónì Higgs wà lóòótọ́[1] àti orísirísi àwọn eruku tuntun tí àjọbáramu adárajùlọ ṣe àsọtẹ́lẹ̀.[2] Ìrètí ni pé LHC yíò wá ìdáhùn is expected to address some of the ọ̀pọ̀ àwọn ìbérè inú físíksì, nípa èyí láti mú ìlọsíwájú bá òye àwọn òfin àdánidá jínjnlẹ̀. Ó ní ẹ̀rọ ìwárí mẹ́fà tí ìkọ̀ọ̀kan wà fún ìwàdìí ohun pàtó kan.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
àtúnṣe- ↑ "Missing Higgs". CERN. 2008. Retrieved 2008-10-10.
- ↑ "Towards a superforce". CERN. 2008. Retrieved 2008-10-10.