Ẹ̀tọ́ ọmọ ènìyàn ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà

Ìwé-òfin ọdún 1999 ni ó ń dáàbòbò Ẹ̀tọ́ ọmọ ènìyàn ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà Human rights in Nigeria.[1] Nígbà tí orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí ṣe àwọn àtúnṣe gbòógì nínú ẹ̀tọ́ ọmọ ènìyàn ní abẹ́ ìwé-òfin yìí, àjọ Àbọ̀ àwọn Ẹ̀tọ́ Ọmọ Ẹnìyàn ní orílẹ̀-èdè America ti ọdún 2012 ṣe àfihàn àwọn ibi tó nílò àtúnṣe èyí tó jẹ́:[2] ọṣẹ́ tí àwọn ẹgbẹ́ Boko Haram, ìṣekúpani láti ọwọ́ àwọn ọmọ-ogun ìjọba, àìsí ìdọ́gbà ní àárín ẹgbẹ́ àti ìṣòro pẹ̀lú òmìnira àti sọ̀rọ̀. Èsì àgbáyé ti Àjọ Tó ń mójútó Ẹ̀tó ọmọ ènìyàn tí ọdún 2015 fihàn pé wàhálà tí àwọn ẹgbẹ́Boko Haram ti pọ̀jù, dídẹ́kún ẹ̀tọ́ LGBTIQ àti pé jẹgúdújẹrá àwọn ìjọba pẹ̀lú àwọn ohun tí ó ń tẹ́ḿbẹ́lú ìpò Ẹ̀tọ́ ọmọ ènìyàn in Nigeria.[3]

Ìtàn láti ìgbà òmìnira.

àtúnṣe

Ní àsìkò òmìnira Nàìjíríà ní ọdún 1960 tí ó sì padà sí ìjọ̀ba alágbádá ní ọdún 1999, olórí ìpínlẹ̀ méjì ní orílẹ̀-èdè ní, ẹni tí a dìbò yàn kan, arọ́pò ìjọba ológun kan, àti coups d'état méje, èyí tó túmọ̀ sí ìṣèjọba àwọn ológun lẹ́yìn tí wọ́n fí ipá gba agbára. Coup d'état jé ìjà tó bẹ́ sílẹ̀ láàárín olórí àwọn ológun tí wọ́n ṣàkóso àwọn ìpínlẹ̀ ní ètè àti gba agbára lọ́wọ́ wọ́n. Ó ṣeéṣe kó jẹ́ pé torí olórí náà jẹ́ oníwà ìbàjẹ́ tàbi kò mú ìlérí rẹ̀ ṣe ní àsìkò tó wà lórí òyè. Ní ọdún 1979, Nàìjíría fàyè gba ìjọba alágbádá láti lè dìpbò yan olórí rẹ̀ pẹ̀lú ìwé òfin titun.. Ìwé-òfin yìí fi ààyè gbá ẹ̀tọ́ ọmọ ènìyàn tí wọ́n máa ń tẹ̀mọ́lẹ̀.

Àsìkò Ọ̀gágun Ibrahim Babangida, láàárín àwọn yòókù máa ń fi ẹ̀tọ́ ọmọ ènìyàn dú àwọn ará-ìlú.[4]

Àwọn ìtọ́ka sí

àtúnṣe
  1. Amnesty International Nigeria (2019). "Nigeria : Human Rights Agenda". Amnesty International Nigeria. https://www.justice.gov/eoir/page/file/1168876/download&ved=2ahUKEwjypYKt4qfuAhUJZcAKHflOA_4QFjASegQIChAB&usg=AOvVaw225OVr6XIURwPLofYYjpU6. [Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
  2. Bureau of Democracy, Human Rights and Labor. Human Rights Practices for 2012. 2012.
  3. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named :0
  4. McCarthy-Arnolds,Eileen. "Africa, Human Rights, and the Global System: The Political Economy of Human Rights in a Changing World". 30 December 1993