Ẹgbẹ́ òṣèlú

Ẹgbẹ́ òṣèlú jẹ́ ẹgbẹ́ tí àwọn òṣèlú tí ìmọ̀, òye àti èròǹgbà jọra dá sílẹ̀ láti díje dupò òṣèlú ní orílẹ̀ èdè tí wọ́n bá lẹ́tọ̀ọ́ rẹ̀ lábẹ́ òfin. Ìfojúsùn gbogbo ẹgbẹ́ òṣèlú ni láti jẹ àwọn ipò òṣèlú tí ó bá ṣí sílẹ̀ lórílẹ̀ èdè wọn. [1]

Iye ẹgbẹ́ òṣèlú tí ó wà ní NàìjíríàÀtúnṣe

Gẹ́gẹ́ bí àkọsílẹ̀ ti Independent National Electoral Commission|INEC, àpapọ̀ ẹgbẹ́ òṣèlú tó wà ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà jẹ́ ókànléláàdọ́rùn-ún (91). [2]

Àtòjọ ẹgbẹ́ òṣèlú tó wà lórílẹ̀ èdè Nàìjíríà láti 1999 di 2018Àtúnṣe


Àtòjọ ẹgbẹ́ òṣèlú tó wà lórílẹ̀ èdè Nàìjíríà lọ́wọ́́lọ́wọ́Àtúnṣe

Àwọn Ìtọ́kasíÀtúnṣe

  1. "Political Parties". National Democratic Institute. 2019-10-11. Retrieved 2019-12-19. 
  2. "Political Parties – INEC Nigeria". INEC Nigeria – Independent National Electoral Commission. 2019-02-23. Retrieved 2019-12-19. 
  3. "A NEW DAWN". 
  4. "Advanced Peoples Democratic Alliance | Stronger Together". 
  5. "The BOOT Party". 
  6. https://kowaparty.com.ng/
  7. "Democracy for People | Global Affairs and Other Info". Peoplesdemocraticparty.net. 2015-09-11. Retrieved 2015-12-24. 
  8. Independent National Electoral Commission Nigeria, October 2012
  9. "List of 91 Nigeria Political Parties and their acronyms (2019) - ABOUT NIGERIANS". ABOUT NIGERIANS. 2019-01-19. Retrieved 2019-12-19. 

[1]

  1. "Political Parties". National Democratic Institute. 2019-10-11. Retrieved 2019-12-19.