People's Democratic Party

Ẹgbẹ Oṣelu

Peoples Democratic Party [PDP] (Ẹgbẹ́ Dẹmokrátíkì àwọn Aráàlú) jẹ́ ẹgbẹ́ òṣèlú alátakò ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Wọ́n dá ẹgbẹ́ òṣèlú yìí sílẹ̀ lọ́dún 1998. Àwọn ni ọmọ ẹgbẹ́ wọn ṣe ìjọba àpapọ̀ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà títí di ọdún 2015 kí ẹgbẹ́ òṣèlú All Progressives Congress tó gbàjọba àpapọ̀ lọ́wọ́ wọn. Ààrẹ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà mẹ́ta ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀; Olúṣẹ́gun Ọbásanjọ́, Umaru Musa Yar'Adua àti Goodluck Jonathan ni ẹgbẹ́ yìí jẹ kí ẹgbẹ́ APC tó dà wọ́n lágbo nù lọ́dún 2015, tí Ààrẹ Muhammadu Buhari tí ẹgbẹ́ APC fi wọlé gẹ́gẹ́ bí Ààrẹ.

Peoples Democratic Party
ChairmanUche Secondus
Akọ̀wé ÀgbàAbubakar Kawu Baraje
Ìdásílẹ̀1998 (1998)
IbùjúkòóWadata Plaza, Michael Okpara Way, Wuse, Abuja
Ọ̀rọ̀àbáModerate
Official coloursGreen, white, red
Ibiìtakùn
PDP, INEC
PDP, Yar' adua 2007
Ìṣèlú ilẹ̀ NigeriaÀwọn Ìtọ́kasíÀtúnṣe