Ẹgbẹ́ kárbọ̀nù

Àdàkọ:Periodic table (group 14) Ẹgbẹ́ kárbọ̀nù ni ẹgbẹ́ tábìlì ìdásìkò kan tó ní kárbọ̀nù (C), sílíkọ́nù (Si), jẹ́rmáníọ́mù (Ge), tanganran (Sn), òjé (Pb), àti flẹ́rófíọ́mù (Fl).

Kẹ́míkà

àtúnṣe

Bi àwon egbe yioku, àwon elimenti inu egbe yi ni eto bi itolera elektronu wo se ri, agaga igba to bosode, eyi unkopa ninu iwa kemika won:

Z Ẹ́límẹ̀ntì Iye elektronu ninu igba kookan
6 Carbon 2, 4
14 Silicon 2, 8, 4
32 Germanium 2, 8, 18, 4
50 Tin 2, 8, 18, 18, 4
82 Lead 2, 8, 18, 32, 18, 4
114 Flerovium 2, 8, 18, 32, 32, 18, 4 (predicted)