Ọ̀dùnkún

Ohun ọ̀gbìn fún jíjẹ

Taxonomy not available for Solanum; please create it automated assistant

'Ọ̀dùnkú tàbí ànàmọ́ ( /pəˈtt/) tí èdè àdámọ̀dì rẹ̀ jẹ́ Solanum tuberosum jẹ́ ìkan lára àwọn oúnjẹ afáralókun tí ó ma ń hù láti inú ilẹ̀ tí ó ma ń takùn kálẹ̀ nígbà tí ó bá ń ta.

Àdàkọ:Speciesbox/hybrid name
Potato cultivars appear in a variety of colors, shapes, and sizes.
Ìṣètò onísáyẹ́nsì [ edit ]
Irú:
Ìfúnlórúkọ méjì
Template:Taxonomy/SolanumSolanum tuberosum
Synonyms

see list

Ìrísí rẹ̀

àtúnṣe
 
Morphology of the potato plant; tubers are forming from stolons.

Ọ̀dùnkún ni ó jẹ́ ìkan lára àwọn ẹbí iṣu tí ó lè lò tó ọdún méjì kí ó tó bàjẹ́ tán. Ànàmọ́ tí ó bá gbo tí ó sì ta dára dára ma ń gún níwọ̀n bàtà kan 1 metre (3.3 ft) Ewé rẹ̀ ma ń ní ẹ̀ka mẹ́ta mẹ́ta lára ẹ̀ka igi kọ̀ọ̀kan. Ìrísí ewé rẹ̀ náà ma ń ní àwọ̀ oríṣiríṣi bíi ìtànṣán Oòrùn (pink), sí àwọ̀ aró àti pọ́pù pàá pàá jùlọ bí kòkòrò bá ti ń jẹ ewé rẹ̀.[1] Orísiríṣi ọ̀nà ni wọ́n ma ń gbà gbin ọ̀dùnkún, wọ́n lè gbi ọ̀dùkún fúnra rẹ̀ kí ó sì hu ewé jáde lẹ́yìn tí ó bá ti jẹrà tán tí ó ṣe ṣetán láti ta. Wọ́n lè gbi òkun ewé rẹ̀ tí ìyẹn náà yóò sì ta egbò tí ọ̀dùnkún yóò sì tibẹ̀ hù pẹ̀lú. Èyíkéyí ọ̀nà tí wọn kí báà gbà gbìn in, ọ̀dùnkún yóò hu ewé, ó sì tún ma ń mí kí afẹ́fẹ́ lè wọ inú rẹ̀ nígbà tí ó bá ń ìdàgbà-sókè lọ́wọ́ àwọn ibi tí ó ń gbà mí Yii ni àwọn onímọ̀ ń pe ní lenticels. Ibi tí ó ń gbà mí yìí ni ó pọ̀ lára rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí ilẹ̀ bá ṣe gbàá láàyè sí. [2] Ọ̀dùnkún ma ń tóbi si nínú ilẹ̀ bí àsìkò bí ọjọ́ bá ṣe ń lọ sí lórí rẹ ni. [3] Lẹ́yìn tí ó bá hu ewé tán ni yóò mú iṣu ànàmọ́ jáde pẹ̀lú àwọ̀ tí ó bá wà lára èyí tí a ti gbìn tẹ́lẹ̀. [4]

Àwọn ìọ́kasí

àtúnṣe
  1. "Solanum tuberosum: Potato". Royal Botanic Gardens Kew. Retrieved 5 May 2024. 
  2. Ewing, E. E.; Struik, P. C. (1992). "Tuber Formation in Potato: Induction, Initiation, and Growth". In Janick, Jules. Horticultural Reviews. pp. 89–198. doi:10.1002/9780470650523.ch3. ISBN 978-0-471-57339-5. 
  3. Amador, Virginia; Bou, Jordi; Martínez-García, Jaime; Monte, Elena; Rodríguez-Falcon, Mariana; Russo, Esther; Prat, Salomé (2001). "Regulation of potato tuberization by daylength and gibberellins". International Journal of Developmental Biology (45): S37–S38. http://www.ijdb.ehu.es/abstract.01supp/s37.pdf. Retrieved 8 January 2009. 
  4. Plaisted, R. (1982). "Potato". In W. Fehr & H. Hadley. Hybridization of Crop Plants.. New York: American Society of Agronomy, Crop Science Society of America. pp. 483–494. ISBN 0-89118-034-6.