Ọ̀gá àwọn Ọmọṣẹ́ Ológun Nàìjíríà
Ọ̀gá àwọn Ọmọṣẹ́ Ológun Nàìjíríà tàbí Ọ̀gá Ilé-iṣẹ́ Ológun Nàìjíríà (Chief of Defence Staff, CDS ní èdè gẹ̀ẹ́sì) ni ọmọṣẹ́ ológun tí ipò rẹ̀ gajùlọ ní àrin àwọn Ilé-iṣẹ́ Ológun Nàìjíríà àti olóri gbogbo àwọn Ilé-iṣẹ́ Ológun Nàìjíríà. Ipò yìí jẹ́ fún ọ̀gá ológun tí Ààrẹ ilẹ̀ Nàìjíríà yàn. Wọ́n dá ipò yìí sílẹ̀ fún ìgbà àkọ́kọ́ lábẹ́ òfin-ìbágbépọ̀ Nàìjíríà ọdún 1979.
Ọ̀gá àwọn Ọmọṣẹ́ Ológun Nàìjíríà Chief of the Defence Staff | |
---|---|
Standard of the Nigerian Defence Forces | |
Ministry of Defence | |
Reports to | Minister of Defence |
Seat | Defence Headquarters, Abuja |
Appointer | Ààrẹ ilẹ̀ Nàìjíríà |
Constituting instrument | Constitution of Nigeria |
Formation | April 1980 |
First holder | Ipoola Alani Akinrinade |
Ọ̀gá àwọn Ọmọṣẹ́ Ológun Nàìjíríà únjíṣẹ́ tààrà fún Ààrẹ ilẹ̀ Nàìjíríà bótitìlẹ́jẹ́pé ìmọ́jútó àwọn Ilé-iṣẹ́ Ológun Nàìjíríà wà lábẹ́ Alákóso Ètò Àbò. Iṣẹ́ àti làákání Ọ̀gá àwọn Ọmọṣẹ́ Ológun Nàìjíríà ni láti dá àti ṣe àwọn iṣe àti ètò fún Àbò Orílẹ̀-èdè àti láti ríi pé àwọn Ilé-iṣẹ́ Ológun wà ní ìmúrasílẹ̀.
'Ọ̀gá Ilé-iṣẹ́ Ológun Nàìjíríà úngba ìrànlọ́wọ́ látọwọ́ àwọn Ọ̀gá Ilé-iṣẹ́ Ológun kọ̀ọ̀kan yìókù:
Àtòjọ Ọ̀gá àwọn Ọmọṣẹ́ Ológun
àtúnṣeNo. | Chief of Defence Staff | Bósí ipò | Kúrò ní ipò | Time in office | Ẹ̀ka ilé-iṣẹ́ ológun | |
---|---|---|---|---|---|---|
1 | Ipoola Alani Akinrinade | Lieutenant GeneralApril 1980 | 2 October 1981 | Àdàkọ:Age in years and months | Adigun Nàìjíríà | |
2 | Gibson Jalo | Lieutenant General2 October 1981 | 31 December 1983 | 2 years, 90 days | Adigun Nàìjíríà | |
3 | Domkat Bali | General1 January 1984 | 10 January 1990 | 6 years, 9 days | Adigun Nàìjíríà | |
4 | Sani Abacha | General10 January 1990 | 17 November 1993 | 3 years, 311 days | Adigun Nàìjíríà | |
5 | Oladipo Diya | Lieutenant General17 November 1993 | 21 December 1997 | 4 years, 34 days | Adigun Nàìjíríà | |
6 | Abdulsalami Abubakar | General21 December 1997 | 9 June 1998 | 170 days | Adigun Nàìjíríà | |
7 | Al-Amin Daggash | Air Marshal9 June 1998 | 29 May 1999 | 354 days | Ajagun Ojúòfurufú Nàìjíríà | |
8 | Ibrahim Ogohi | Admiral29 May 1999 | 27 June 2003 | 4 years, 29 days | Ajagun Ojúomi Nàìjíríà | |
9 | Alexander Ogomudia | General27 June 2003 | 1 June 2006 | 3 years, 26 days | Adigun Nàìjíríà | |
10 | Martin Luther Agwai | General1 June 2006 | 25 May 2007 | 358 days | Adigun Nàìjíríà | |
11 | Owoye Andrew Azazi | General25 May 2007 | 20 August 2008 | 1 year, 118 days | Adigun Nàìjíríà | |
12 | Paul Dike | Air Chief Marshal20 August 2008 | 8 September 2010 | 1 year, 353 days | Ajagun Ojúòfurufú Nàìjíríà | |
13 | Oluseyi Petinrin | Air Chief Marshal8 September 2010 | 5 October 2012 | 2 years, 27 days | Ajagun Ojúòfurufú Nàìjíríà | |
14 | Ola Ibrahim | Admiral5 October 2012 | 16 January 2014 | 1 year, 103 days | Ajagun Ojúomi Nàìjíríà | |
15 | Alex Sabundu Badeh | Air Chief Marshal16 January 2014 | 13 July 2015 | 1 year, 178 days | Ajagun Ojúòfurufú Nàìjíríà | |
16 | Abayomi Gabriel Olonisakin | General13 July 2015 | Incumbent | 9 years, 142 days | Adigun Nàìjíríà |
Itokasi
àtúnṣeExternal links
àtúnṣeChief Defence staff Nigeria Archived 2022-05-26 at the Wayback Machine.