Ogagun Owoye Andrew Azazi (rtd) (1 February 1952 – 15 December 2012) je oga agba fun oro abo ara Naijiria to sise bi Oludamoran Abo Orile-ede fun Aare Goodluck Jonathan, o tun sise bi Oga awon Omose Ologun (CDS) ile Nigeria, ati Oga awon Omose Agbogun (COAS). Ki o to di oga awon omose agbogun, ohun lo je Alase Gbogbo Osise (GOC) Eka 1k Ile-ise Agbogun Naijiria to budo si Kaduna.

Owoye Andrew Azazi
National Security Adviser, Nigeria
In office
2010–2012
Arọ́pòSambo Dasuki
Chief of Defence Staff
In office
2007–2008
AsíwájúMartin Luther Agwai
Arọ́pòPaul Dike
Chief of Army Staff
In office
2006–2007
AsíwájúMartin Luther Agwai
Arọ́pòLuka Yusuf
General Officer Commanding 1 Division Nigerian Army
In office
January 2005 – July 2006
AsíwájúMaj-Gen. S.A. Asemota
Arọ́pòMaj-Gen. L.O. Jokotola
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí(1953-02-01)1 Oṣù Kejì 1953
Bayelsa State, Nigeria
Aláìsí15 December 2012(2012-12-15) (ọmọ ọdún 60)
Okoroba, Bayelsa State, Nigeria
Military service
Allegiance Nigeria
Branch/serviceNigerian Army
RankGeneral