Ọ̀rọ̀:Dres the rapper

Àdàkọ:BLP sources

Dres
Orúkọ àbísọAndres Vargas-Titus
Wọ́n tún mọ̀ọ́ bíiDres
Ọjọ́ìbí18 Oṣù Kẹta 1967 (1967-03-18) (ọmọ ọdún 57)
Ìbẹ̀rẹ̀Queens, New York, U.S.
Irú orinHip hop
Occupation(s)Rapper, actor
Years active1989–present
LabelsMercury/PolyGram Records
Ground Control Records
Tommy Boy Entertainment
Associated actsBlack Sheep
Native Tongues

Andres "Dres" Vargas-Titus) (ọjọ́ ìbí jẹ́ oṣù kẹta, ọjọ́ kejidinlogun, ọdún 1967) jẹ́ Òṣeré Hip hop ni orile Ede Amerika. Ó jẹ́ olori fún àwọn Òṣeré tí orúkọ ègbé wọn jẹ́ Alternate Hip hop duo Black sheep group, kí ó tó dá dúró.

Dres dá egbe Black sheep kalẹ ni 1989 pẹ̀lú Mista Lawnge. Àwọn mejeeji kọ́kọ́ ṣeré papọ ni 1991 tí wọn pé àkọlé orin wọn ní De La Soul. Ó kópa ńinu àwo orin tí àkọlé rẹ jẹ "Fanatic of The B word.[1]

Àwọn ère amohunmàwòrán tí ó kopa ninu rẹ

àtúnṣe

Itọ́kasi

àtúnṣe
àtúnṣe

Àdàkọ:Authority control


Àdàkọ:US-hiphop-bio-stub

Return to "Dres the rapper" page.