Àkíyèsí pàtàkì

àtúnṣe

Mo kí oníṣẹ́ @Royalesignature fún iṣẹ́ takuntakun ń ṣe lórí Wikipedia Yorùbá. Síbẹ̀, mo fẹ́ pe àkíyèsí yín sí àwọn àyọkà tuntun tí ẹ ń dá sílẹ̀ wípé wọn kò kún tó wọn kò sì fi bẹ́ẹ̀ bójúmu fún Wikipedia èdè Yorùbá. A gbà yín níyànjú kí ẹ ṣe àkọkún àwọn àyọkà náà kí wọ́n lè dùn ún kà siwájú si. Àwọn àyọkà náà kò jápọ̀ mọ́ àwọn àyọkà mìíràn lórí Wikipedia èdè Yorùbá.

Ẹ kúuṣẹ́.Agbalagba (ọ̀rọ̀) 16:29, 6 Oṣù Ṣẹ̀rẹ́ 2025 (UTC)Reply

Ẹ ṣeun pupọ àtúnṣe yíò wá laipe Royalesignature (ọ̀rọ̀) 05:22, 7 Oṣù Ṣẹ̀rẹ́ 2025 (UTC)Reply