Ọọ̀ni Ajila Oorun
Ooni Ajila Oorun ní Ọọ̀ni Ilé-Ifẹ̀ ẹlẹ́ẹ̀kọkàndínlọ́gbọ̀n, tó jẹ́ olórí ìbílẹ̀ Ilé-Ifẹ̀, tí ń ṣe orírun àwọn Yorùbá. Ó jẹ oyè Ọọ̀ni lẹ́yìn tí Ọọ̀ni Omogbogbo wàjà, Ọọ̀ni Adejinle sì ló jẹ oyè yìí lẹ́yìn tí òun náà wàjà.[1]
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ Dayo, Ologundudu (2008). The cradle of Yoruba culture. Nigeria: Centre for spoken words. p. 206. ISBN 978-0615220635. https://books.google.com/books?id=Vn8uAQAAIAAJ&q=Ooni+Ojigidiri&dq=Ooni+Ojigidiri. Retrieved July 30, 2015.