Ooni Omogbogbo ni Ọọ̀ni Ilé-Ifẹ̀ ẹlẹ́ẹ̀kejìdínlọ́gbọ̀n, tó jẹ́ olórí ìbílẹ̀ ti Ilé-Ifẹ̀ tí ń ṣe orírun àwọn Yorùbá. Ọọ̀ni Ademilu ló wàjà tí Omogbogbo fi jẹ ọba, léyìn rẹ̀ ni Ọọ̀ni Ajila Oorun jẹ oyè Ọọ̀ni.[1]

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. Dayo, Ologundudu (2008). The cradle of Yoruba culture. Nigeria: Centre for spoken words. p. 206. ISBN 978-0615220635. https://books.google.com/books?id=Vn8uAQAAIAAJ&q=Ooni+Ojigidiri. Retrieved July 30, 2015.