Arẹ̀mọ Ọba
(Àtúnjúwe láti Ọmọ-Ọba)
À̀rẹ̀̀mọ Ọba ni a lè pè ní ọmọ bíbí inú tàbí ẹ̀jẹ̀ ọba tí ó jẹ́ ọkùnrin. Arẹmọ le jẹ ọmọ Arẹmọ ìtẹ́ ti yoo j'ọba láìpẹ́. Àrẹ̀mọ lè jẹ́ àkọ́bí tàbí àbíkẹ́yìn tàbí ọmọ-ọmọ ẹni tí ó ti jẹ ọba rí tàbí ẹni tí ó wà ní orí ìtẹ́-ọba lọ́wọ́lọ́wọ́ ní inú ìlú kan. A tún lè sọ sọ wípé àwọn ọmọ ọkùnrin tí wọn á tilé ọba wa ni wọn n oe ní Arẹ̀mọ, àwọn ni ipò ọba ma ń sábà á kàn nígbà tí oyè ọba bá tọ́sí ìdílé wọn. Ní ilẹ̀ Yorùbá, àwọn obìnrin kìí sábà á jẹ ọba látàrí òfin, ìṣẹ̀dálẹ̀ àti ìṣèlú ilẹ̀ Yorùbá .[1]
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ Cassell's Latin Dictionary, ed. Marchant & Charles, 260th thousand