1838 Ursa jẹ́ plánẹ́tì kékeréibi ìgbàjá ástẹ́rọ́ìdì. Paul Wild ni ose awari planeti yii ni ogun jo, osu kewa odun 1971. O ni odun marun ati orinle ruigba ojo lati yipo kilomita 34.87 ni diayamita. A fi oruko re sori eranko Igbo Ursula, omo re Urs igbo ni swistzerland.