2008 Benin flood
Ìṣẹ̀lẹ̀ ìkun Benin ọdún 2008 gba gbogbo orílẹ̀-èdè Benin láàárín July sí October 2008, tí ó sì pa àwọn orílé-èdè tí ó fi ẹgbẹ kín-in bí Burkina Faso, Mali, Mauritania, Niger àti Togo lára . Gẹ́gẹ́ bí àkọsílẹ̀ àwọn ẹgbẹ́ Red cross tí Benin, ìkun omi Benin yìí pa àwọn tí ó tó ẹ̀ẹ̀dẹ́gbàrin ènìyàn (7000) lára, tí àwọn ọmọ tí ó tó 1,560 sí pàdánù ibùgbé wọn tí wọn kò mọ ilé mọ. Ní ọjọ́ 19 August 2008 àjọ àgbáyé WHO ṣe òṣùwọ̀n pé ìkún omi yìí tí sọ àwọn tí ó tó 150,000 èèyàn di aláìní ilé lórí. [1][2]
Àwọn 500,000 èèyàn ni wọn wà ní inú fu àyà fu pé kí ìkun omi mìíràn kí ó má gbé wọn lọ.
Odò Mono River and Ouémé River tí ó ń ṣàn láti Central Benin sí olú ìlú ọrọ̀ ajé ti Cotonou ní agbọn ibí yìí ìṣòro kan wà níbẹ̀. Ọ̀̀sẹ̀ lẹ́yìn tí ìkun tí ó ṣẹlẹ̀ ni July 2008, ọ̀pọ̀ ní àwọn apá ibìkan ní Cotonou tí kò tí ì gbẹ, tí ó sì léwu fún ètò àgọ̀ ara. Àwọn ibi jàǹkàn-jàǹkàn ní inú ìlú yìí ní ó sì fara gbá a jù. Tí àwọn tí ó tọ́ ìdá mẹ́wàá inú ìlú náà sí fara gbá a. Aṣojú ẹ̀ka WHO tí ọ́fíìsì wọn wà ní Cotonou, WHO ọ́fíìsì Ministry fún tí Hygiene, public health and social affairs, gba àwọn èèyàn níyànjú láti kúrò ní agbègbè tí ìṣẹ̀lẹ̀ náà tí ń ṣẹlẹ̀, tí àwọn náà ó sì kó pa kékeré láti kó àwọn èèyàn kúrò níbi tí ìṣẹ̀lẹ̀ náà tí ń ṣẹ̀ .[3].[3]"[3][3][3]
Àwọn ìtọ́kasí.
àtúnṣe- ↑ "Floods in West Africa raise major health risks". World Health Organization, Geneva. Archived from the original on 15 May 2009. Retrieved May 10, 2009. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "BENIN: Half million potential flood victims : WHO". IRIN, UN Office for the Coordination of Humanitarian Affairs. Archived from the original on January 4, 2009. Retrieved May 10, 2009. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ 3.0 3.1 3.2 3.3 3.4 Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs namedIRIN2