2009 (ẹ́ẹ̀sánlélẹ́gbẹ̀rúnméjì tabi ẹ̀sánlélẹ́gbẹ̀rúnmèjì tabi ẹgbẹ̀rún méjì lé lẹ́ẹ̀sán) jẹ́ ọdún tówọ́pọ̀ tó bẹ̀rẹ̀ ní ọjọ́bọ̀ nínú Kàlẹ́ndà Gregory.