2Shortz
William Orioha tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí 2Shortz ni wọ́n bí ní ọjọ́ Kẹta oṣù Kẹta, ọdún 1979 (3 March 1979). Jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, olùkọ orin àti ọ̀kọrin ráápù tẹ́lẹ̀, àmọ́ tí ó ti di ayàwòrán àti olùgbéré ìtàgé jáde ní orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà báyí.[2] Ó gba àmì-ẹ̀yẹ fún Best Collaboration eré The Headies ní ọdún 2006.[3] Àwo orin tí ó gbé 2Shortz jáde tí ó pè ní Pirated Copy ni ó gbé jáde ní ọdún 2004, tí ó sì tún fi àwọn orin àdákọ mẹ́ta lée lórí tí ó pè àkọ́lé wọ́n ní: "Carry Am Go", "Odeshi" àti "Delicious".[4] Ó gbe awo orin èkejì jáde ní ọdún 2005 tí ó pe ní 'Original Copy, nígbà tí ó gbe awo Ìkẹjà tí ó pe ní Commercial Avenue jáde ní ọdún 2007. Òun ló tún kọ Music Business tí ó gbe jáde ní ọdún 2008. Ọdún 2010 ni ó kọ I am William tí ó sì kọLoud Silence ní ọdún 2016.[5] Èdè Gẹ̀ẹ́sì, èdè Igbo àti èdè àdàmọ̀dì Gẹ̀ẹ́sì (pigin) ni 2Shortz fi ma ń kọrin ráápù rẹ̀.[6]
2Shotz | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | William Orioha 3 Oṣù Kẹta 1979 Surulere, Lagos State, Nigeria |
Iléẹ̀kọ́ gíga | Lagos State University |
Iṣẹ́ |
|
Ọmọ ìlú | Umuahia, Abia State |
Olólùfẹ́ | Precious Jones [1](m. 2013; separated 2015) |
Àwọn ọmọ | 1 |
Awards | Best Collaboration at the The Headies 2006 |
Musical career | |
Irú orin | Hip hop |
Instruments | Vocals |
Years active | 1997–2016 |
Labels | Umunnamu Music |
Associated acts | |
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ Tayo, Ayomide (22 December 2015). "2Shotz Rapper responds to domestic abuse allegations". Pulse NG. https://www.pulse.ng/entertainment/celebrities/2shotz-rapper-responds-to-domestic-abuse-allegations/8hhevlk. Retrieved 24 November 2019.
- ↑ Okanlawon, Taiwo (16 November 2019). "Meet 10 Nigerian artistes who faded from the scene". P.M. News. https://www.pmnewsnigeria.com/2019/11/16/meet-10-nigerian-artistes-who-faded-from-the-scene. Retrieved 24 November 2019.
- ↑ "Winners - The Headies 2006". Hip Hop World Magazine. Archived from the original on 9 March 2019. Retrieved 24 November 2019.
- ↑ Sean, DJ (11 November 2013). "[TB ~ 2shotz - CARRY AM GO + ODESHI + DELICIOUS Remix ft. Big Lo"]. AceWorldTEAM. http://aceworldteam.com/2013/11/11/2shotz. Retrieved 24 November 2019.
- ↑ Onyekwena, Chiagoziem (25 October 2010). "2-Shotz - the Veteran, the Visionary". Nigerian Entertainment Today. http://thenet.ng/2-shotz-the-veteran-the-visionary. Retrieved 24 November 2019.
- ↑ Sowoolu, Lolade (23 July 2010). "2Shotz drops album No. 5". The Vanguard Newspapers. https://www.vanguardngr.com/2010/07/2shotz-drops-album-no-5. Retrieved 24 November 2019.