Brymo
Ọlawale Ọlọfọrọ (tí orúkọ àbísọ rẹ̀ ń jẹ́ Olawale Ibrahim Ashimi; tí a bí ní ọjọ́ kẹsàn-án, oṣù karùn-ún, ọdún 1986),[1][2] tí orúkọ ìnagijẹ rẹ̀ ń jẹ́ Brymo, jẹ́ olórin orílẹ̀-èdè Naijiria, akọrin, oṣèré orí-ìtàge àti òǹkọ̀wé. Ó tẹwọ́bọ̀wé iṣẹ́ pẹ̀lú Chocolate City ní ọdún 2010, àmọ́ wọ́n fi ẹ̀sún kàn án pé ó tàpa sí òfin ìwé-iṣẹ́ náà ní ọdún 2013.[3][4]
Brymo | |
---|---|
Brymo performing "Let Us Be Great" for Ndani Sessions in November 2018 | |
Background information | |
Orúkọ àbísọ | Olawale Ashimi |
Ọjọ́ìbí | 9 Oṣù Kàrún 1986 Okokomaiko, Ojo, Lagos State, Nigeria |
Irú orin | |
Occupation(s) |
|
Instruments | Vocals, Keyboard, Guitar |
Years active | 1999–present |
Labels | Independent |
Associated acts |
|
Àtòjọ orin rẹ̀
àtúnṣe- Studio albums
- Brymstone (2007)
- The Son of a Kapenta (2012)
- Merchants, Dealers & Slaves (2013)
- Tabula Rasa (2014)
- Klĭtôrĭs (2016)
- Oṣó (2018)
- Yellow (2020)
- “9 – Esan” (2021)
- “9 – Harmattan & Winter” (2021)[5]
- Yellow (2022)
- Theta (2022)
- Compilation and live albums
- Trance (2015)
- Live! at Terra Kulture Arena (2019)
- EPs
- A.A.A (with Skata Vibration as A.A.A) (2019)
- Libel (EP) (2020)
Àwọn ìwé rẹ̀
àtúnṣe- Oriri's Plight (2018)
- Verses (2020)
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ Ade-Unuigbe, Adesola (9 May 2014). "FAB Entertainment: Brymo Spends His Birthday Morning Getting A Spa Treatment". Fab Magazine. Archived from the original on 6 June 2014. Retrieved 5 June 2014. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Brymo Biography (Nigerian Artist)". Nigeria Music Network. 24 March 2014. Archived from the original on 13 November 2013. Retrieved 5 June 2014. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ Osagie Alonge (25 October 2013). "NET Special Report: Chocolate City Vs Brymo, see you in court guys!". Nigerian Entertainment Today. Archived from the original on 13 May 2016. Retrieved 22 May 2016. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "'I know the court can't save me', Brymo says he left Chocolate City over breach of contract". Nigerian Entertainment Today. 20 June 2013. Archived from the original on 21 June 2016. Retrieved 22 May 2016. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "REVIEW: Brymo - 9: Esan [ALBUM]". Pulse Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2021-09-11. Retrieved 2021-10-02.