ABS F.C.
ABS F.C. tí àpèjá rẹ̀ ń Abubakar Bùkọ́lá Saraki FC jẹ́ ikọ̀ ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù àfẹsẹ̀gbá tí ó fìkàlẹ̀ sí ìlú [[Ìlọrin] lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Wọ́n gba ìgbéga sí ìdíje Àgbábuta Bọ́ọ̀lù Àfẹsẹ̀gbá tí orílẹ̀ èdè Nàìjíríà sáà ìdíje tí 2009-2010. Wọ́n gbá ìdíje Àgbábuta bọ́ọ̀lù-àfẹsẹ̀gbá àkọ́kọ́ tí Nàìjíríà ní ìlú Ọ̀fà àti Bauchi nígbà tí àtúnṣe ń lọ lọ́wọ́ lórí gbọ̀ngàn ìdárayá tí ìpínlẹ̀ Kwara Kwara State Stadium. Ọdún 2011 ní Bùkọ́lá Sàràkí, tí ó jẹ́ Gómìnà Ìpínlẹ̀ Kwara nígbà náà ra ikọ̀ ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù àfẹsẹ̀gbá-jẹun yìí ní N250,000:00
Full name | Abubakar Bukola Saraki Football Club | ||
---|---|---|---|
Ground | Kwara State Stadium Ilorin, Nigeria (Capacity: 18,000) | ||
Chairman | Seni Saraki | ||
Team Manager | A C C chukuemeka | ||
Technical Advisor | Erasmus Onu | ||
Coach | Henry Makinwa | ||
League | Nigeria National League | ||
Website | Club home page | ||
|
Èyí ni ó sọ ikọ̀ ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù àfẹsẹ̀gbá yìí di àti JUTH F.C. di ikọ̀ ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù àfẹsẹ̀gbá tí kìí ṣe tí Ìjọba ìpínlẹ̀ kankan.[1]
Lọ́dún 2011 ni wọ́n pàrọ̀ orúkọ ikọ̀ ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù àfẹsẹ̀gbá yìí kúrò ní Bukola Babes sí ABS (Abubakar Bukola Saraki) FC.[2]
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ Bassey, Ime (August 13, 2011). "Adama puts Bukola Babes up for sale". Vanguard.
- ↑ Ahmadu, Samuel (2016-11-10). "Abubakar Bukola Saraki FC return to Nigeria Professional Football League". Goal.