Bukola Saraki

Olóṣèlú Nàìjíríà, Waziri ti Ilorin, Aare ile igbimo asofin agba ile Nàìjíríà 2015-2019

Àdàkọ:DMCÀdàkọ:Merge partner

Bukola SarakiBukola Saraki

Bukola Abubakar Saraki
President of the Nigerian Senate
In office
9 June 2015 – 11 June 2019
DeputyIke Ekweremadu
AsíwájúDavid Mark
Arọ́pòAhmed Ibrahim Lawan
Senator of the Federal Republic of Nigeria
In office
29 May 2011 – 11 June 2019
AsíwájúGbemisola Saraki
Arọ́pòIbrahim Yahaya Oloriegbe
ConstituencyKwara Central Senatorial District
Governor of Kwara State
In office
29 May 2003 – 29 May 2011
AsíwájúMohammed Alabi Lawal
Arọ́pòAbdulfatah Ahmed
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí
Olubukola Abubakar Saraki

19 Oṣù Kejìlá 1962 (1962-12-19) (ọmọ ọdún 61)
London, United Kingdom
Ọmọorílẹ̀-èdèNigerian
Ẹgbẹ́ olóṣèlúPeople's Democratic Party (2000–2014; 2018–present)
Other political
affiliations
All Progressives Congress (2014–2018)
(Àwọn) olólùfẹ́Toyin Saraki
Àwọn òbíOlusola Saraki
EducationBachelor of Medicine, Bachelor of Surgery
Alma materLondon Hospital Medical College
ProfessionPhysician and Politician

Abubakar Bukola Saraki, MBBS, Àdàkọ:Post-nominals (ojọ́ ìbí rẹ̀ ni ni ọjọ kọkandinlógún, osù kọkànlá, ọdún 1962) jẹ́ olósèlú kan ní ilé Nàìjíría. Ó jẹ́ Ààrẹ Ketàlá ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin orílé èdè Nàìjíríà láti ọdún 2015-2019, àti pé òun náà ni Ààre kẹjọ fún ilé ìgbìmò asòfin ní orílé Èdè Nàìjíríà.[1][2] Ó jẹ́ Gómìnà ní ìpínlè Kwara láti ọdún 2003 títí dé 2011 lábé àwọn ọmọ ẹgbẹ PDP ( People Democractic Party)[3][4] ó sì tún jẹ́ aṣojú Central Senatorial District tí ìpínlẹ̀ Kwara ní láàrin ọdún 2011 sí 2019, ó lọ ṣáà àkókò lábẹ́ abé ẹgbẹ́ òsèlú People Democratic Party àti ṣáà kejì lábẹ́ ẹgbẹ́ òsèlú All Progressive Congress.[5][6][7]

Ní ọjọ tí o gbẹ̀yìn oṣù keje ọdún 2018, Ní Sàràki kúrò ní Ẹgbẹ́ APC, tí ó sì padà sí ẹgbẹ́ PDP ti ó wà ní àkọkọ́, tí ó fí dì ààrẹ ẹgbẹ́ alátàkò .[8][9][10] Sàràki kéde pé òun yóò wà lára àwọn tí wọn sára fún Ìpo ààrẹ Orile èdè Nàìjíríà, tí o sí rà iwe tí wọn ń pé ní Presidential Ticket ní ìdìbò ọdún 2019,[11]amò nínú ìbò abẹlé, ó fi ẹ̀yin lè lẹ nígbà tí Atiku Abubakar jáwé olúborí. Amò ó tún tẹ̀síwájú láti kéde pé òun ní Olùdarí Àgbà ẹgbẹ́ tí ó ń ṣètò ìponlogo fún Atiku Abubakar tí n du ipò ààrẹ ní idibo gbogbogboo ni ọdún 2019, sùgbóọ́n òun náà fẹ̀hìn lè lẹ nígbà tí Ààrẹ Muhammadu Buhari jáwé olúborí tí ó pàdé dì ààrẹ fún orílé Èdè Nàìjíríà.[12][13]

Ìdílé

àtúnṣe

Wọn bí Saraki ni ọjọ kọkàndínlógún oṣù Kejìlá ní ọdún 1962 ní Lọ́ǹdònù[14] tí ìyá rẹ̀ ń jẹ́ Florence Morenike Sàràki àti bàbá rẹ̀ Olusola Saraki, tí òun náà nígbà kan rí tí jẹ́ Adarí ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin ní orílé èdè Nàìjíríà.[15] Bukola Saraki fẹ Toyin Saraki (née Ojora), tí wọn sì jọ bí ọmọ Mẹ́rin.[16]

Ètò Ẹkọ

àtúnṣe

Sàràki jáde ní ilé ìwé Ẹkọ gíga King's College, ni Lagos, níbi tí o tí jáde ní ọdún 1978. Ó kúrò níbẹ ó lọ sí Cheltenham College, èyí tí o jẹ́ ilé ìwé (boarding school) ni United Kingdom láti 1979 titi dé 1981. Tí o túnbọ̀ tẹsiwaju láti lọ kàwé sí ní Fásitì tí wá ní London ni ilé ìwòsan tí London Medical college láti ọdún 1982 tí tí dì 1987 ní bí tí o tí kàwé gbọyè Bachelor of Medicine, Bachelor of Surgery.[17]

Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀ Iṣé Ṣiṣe

àtúnṣe

Saraki ṣíṣe ní ilé ìwòsan Rush Green ni Essex gẹ́gẹ́ ní Oníwòsàn ní ọdún 1988 sí òdun 1989. Saraki tun je Olùdarí ilé iṣẹ ìfowópamọ́si ní orílé Èdè Nàìjíríà tí orúkọ ilé ìfowópamọ́si náà sì ń jẹ Société Générale (Nig) Ltd láti ọdún 1990 si 2000.[18] ní ọdún 2000, Ààrẹ Olusẹgun Õbásanjọ́ fí Saraki jẹ́ Olùrànlọ́wọ́ pàtàkì sí ààrẹ lórí bí àṣẹ ń náwó.[19][20]

 1. "How my brother 'failed' Kwara - Saraki's sister" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2019-03-16. Retrieved 2022-02-24. 
 2. Ibifubara Abbiyesuku (16 May 2022). "#RoadTo2023 Spotlight: Profile of Abubakar Bukola Saraki | Presidential Series". Retrieved 28 June 2022. [Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
 3. Staff, Ebunoluwa Ojo | Entrepreneurs ng (2019-09-08). "Bukola Saraki - Biography And Political History Of Abubakar Bukola Saraki". Entrepreneurs In Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-05-28. [Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
 4. Premium Times (9 June 2015). "Bukola Saraki elected Senate President". Premium Times. https://www.premiumtimesng.com/news/headlines/184666-breaking-bukola-saraki-elected-senate-president-2.html. 
 5. Staff, Ebunoluwa Ojo | Entrepreneurs ng (2019-09-08). "Bukola Saraki - Biography And Political History Of Abubakar Bukola Saraki". Entrepreneurs In Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-05-28. [Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
 6. Premium Times (9 June 2015). "Bukola Saraki elected Senate President". Premium Times. https://www.premiumtimesng.com/news/headlines/184666-breaking-bukola-saraki-elected-senate-president-2.html. 
 7. DEMOLA AKINYEMI (8 March 2013). "Bukola Saraki: The new face of Kwara politics?". Vanguard. https://www.vanguardngr.com/2013/03/bukola-saraki-the-new-face-of-kwara-politics/. 
 8. "Why I decamp from APC to PDP – Bukola Saraki" (in en-US). https://www.sunnewsonline.com/why-i-decamped-to-pdp-bukola-saraki/. 
 9. Nwosu, Philip (31 July 2018). "Why I decamp from APC to PDP – Bukola Saraki". The Sun. https://www.sunnewsonline.com/why-i-decamped-to-pdp-bukola-saraki/. 
 10. Ronke Sanya (31 July 2018). "Senate President Saraki Dumps APC". Channels TV. https://www.channelstv.com/2018/07/31/breaking-senate-president-saraki-dumps-apc/. 
 11. "UPDATED: Saraki declares his intention to run for presidency" (in en-US). https://punchng.com/breaking-saraki-declares-for-presidency/. 
 12. "Saraki named Atiku's Presidential Campaign Council Director General" (in en-US). https://www.vanguardngr.com/2018/10/saraki-tambuwal-wike-fayose-others-named-atikus-presidential-campaign-dg-zonal-coordinators/. 
 13. "Saraki declares intention to run for president in 2023". Punch Newspapers (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2022-01-26. Retrieved 2022-02-23. 
 14. Adams, Odunayo. "Saraki Is A British Citizen - UK Authority". Retrieved 13 June 2019. 
 15. "Bukola Saraki Biography / Profile". www.manpower.com.ng. 2022. 
 16. "Toyin Ojora Saraki". Archived from the original on 26 September 2015. Retrieved 16 September 2015.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
 17. "Bukola Saraki: Profile Of An Ambitious Political Gatekeeper" (in en-US). Archived from the original on 21 August 2018. https://web.archive.org/web/20180821191914/https://guardian.ng/politics/bukola-saraki-profile-of-an-ambitious-political-gatekeeper/. 
 18. "Dr. Abubakar Bukola Saraki". Dr. Abubakar Bukola Saraki. Archived from the original on 8 April 2010. Retrieved 6 December 2009.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
 19. "Senator (Dr.) Abubakar Bukola Saraki". www.senatepresident.gov.ng. Archived from the original on 13 August 2018. Retrieved 13 August 2018.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
 20. "Bukola Saraki: Epitome of service, standard and pace-setting at 50". The Sun. Archived from the original on 24 October 2014. Retrieved 19 December 2012.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)