Aarhus, tabi Århus (Àdàkọ:IPA-da), ni ilu titobijulo keji ni orile-ede Denmark, ilu titobijulo 99run ni Isokan Europe, ati ikefa-titobijulo ni arin awon orile-ede Nordiki. Gege bi ebute pataki ile Denmark, o budo si egbe ilaorun peninsula Jutland ni gbongan onijeografi ile Denmark.

Århus
Århus inner city in 1998, from the South Harbor side
Århus inner city in 1998, from the South Harbor side
Country Denmark
RegionCentral Denmark Region
MunicipalityAarhus Municipality
Area
 • Urban
91 km2 (35 sq mi)
 • Metro
9,997 km2 (3,860 sq mi)
 • Municipal468 km2 (181 sq mi)
Population
 (2010)[2],[1]
 • Urban
242.914
 • Urban density2,636/km2 (6,830/sq mi)
 • Metro
1,228,398 (17 municipalities in East Jutland metropolitan area)
 • Metro density123/km2 (320/sq mi)
 • Municipal
307,119
 • Municipal density656/km2 (1,700/sq mi)
Time zoneUTC+1 (Central Europe Time)
 • Summer (DST)UTC+2

Ìlú tó tóbii sèkejì ní ilè Denmark. Àwon okò ojú omi máa n gúlè sí ibè. Ó ní Yunifásítì kan. Àwon ènìyàn tí ó wà níbè ní 1955 jé 118, 943. Òun ni olú-ìlú A.Co ní Jutland.