Àwọn Erékùṣù Ábákò
Coordinates: 26°28′N 77°05′W / 26.467°N 77.083°W
Àwọn Erékùṣù Ábákò (Abaco Islands) dubule si apaariwa awon Bahama, o si ni awon erekusu gangan Abako Ninla ati Abako Kenke, lapapo mo Wood Cay kekere, Elbow Cay, Lubbers Quarters Cay, Green Turtle Cay, Great Guana Cay, Castaway Cay, Man-o-War Cay, Stranger's Cay, Umbrella Cay, Walker's Cay, Little Grand Cay, ati Erekusu Moore. Fun imojuto, awon Erekusu Abako ni marun ninu awon Ipinaye ile awon Bahama 31: Ariwa Abako, Arin Abako, Guusu Abako, Erekusu Moore, ati Hope Town. Ninu awon ilu to wa ni awon erekusu na ni Marsh Harbour, Hope Town, Treasure Cay, Coopers Town, ati Cornishtown.
The five administrative districts of the Abacos. | |
Jẹ́ọ́gráfì | |
---|---|
Ibùdó | Atlantic Ocean |
Àgbájọ erékùṣù | Àwọn Bàhámà |
Ààlà | 1,681 km2 (649 sq mi) |
Orílẹ̀-èdè | |
Erékùṣù | Abaco |
Ìlú tótóbijùlọ | Marsh Harbour (pop. 5,728) |
Demographics | |
Ìkún | 14,100 (as of 2000) |
Ìsúnmọ́ra ìkún | 8.4 /km2 (21.8 /sq mi) |
Àwọn ẹ̀yà ènìyàn | Àwọn aláwọ̀dúdú ~50%, Àwọn aláwọ̀funfun ~50% |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |