Àwọn Bàhámà (pípè /ðə bəˈhɑːməz/ (Speaker Icon.svg listen)) tabi lonibise bi Orílẹ̀-èdè Àjọni ilẹ̀ awọn Bàhámà, je orile-ede elede Geesi to ni awon erekusu 29, 661 cays, ati 2,387 erekusu kekere 2,387 (apata). O budo si inu Okun Atlantiki ni ariwa Kuba ati Hispaniola (Dominiki Olominira ati Haiti), ariwaiwoorun awon Erekusu Turks ati Caicos, ati guusuilaorun orile-ede Awon Ipinle Aparapo ile Amerika (nitosi ipinle Florida). Apapo iye aala ile re je 13,939 km2 (5,382 sq. mi.), pelu idiye olugbe to to 330,000. Oluilu re ni Nassau. Bi jeografi, awon Bahama wa ni asopo erekusu kanna bi Kuba, Hispaniola (Dominiki Olominira ati Haiti) ati Awon Erekusu Turks ati Caicos.

Commonwealth of The Bahamas
Àjọni ilẹ̀ àwọn Bàhámà
Àsìá Àmì ọ̀pá àṣẹ
Motto"Forward, Upward, Onward Together"
Orin-ìyìn orílẹ̀-èdè"March On, Bahamaland"
Orin-ìyìn ọba"God Save the Queen"
OlúìlúNassau
25°4′N 77°20′W / 25.067°N 77.333°W / 25.067; -77.333
Èdè àlòṣiṣẹ́ English
Àwọn ẹ̀yà ènìyàn  85% Black (esp. West African), 12% European, 3% Other
Orúkọ aráàlú Ará àwọn Bàhámà
Ìjọba Parliamentary democracy and Constitutional monarchy
 -  Monarch Queen Elizabeth II
 -  Governor-General Arthur Dion Hanna
 -  Prime Minister Hubert A. Ingraham
Independence from the United Kingdom 
 -  Self-governing 1967 
 -  Full independence July 10, 1973[1] 
Ààlà
 -  Àpapọ̀ iye ààlà 13,878 km2 (160th)
5,358 sq mi 
 -  Omi (%) 28%
Alábùgbé
 -  Ìdíye 2007 330,549[2] (177th)
 -  1990 census 254,685 
 -  Ìṣúpọ̀ olùgbé 23.27/km2 (181st)
60/sq mi
GIO (PPP) ìdíye 2008
 -  Iye lápapọ̀ $9.228 billion[3] (145th)
 -  Ti ẹnikọ̀ọ̀kan $27,394[3] (38th)
GIO (onípípè) Ìdíye 2008
 -  Àpapọ̀ iye $7.463 billion[3] 
 -  Ti ẹnikọ̀ọ̀kan $22,156[3] 
HDI (2007) 0.845 (high) (49th)
Owóníná Dollar (BSD)
Àkókò ilẹ̀àmùrè EST (UTC−5)
 -  Summer (DST) EDT (UTC−4)
Ìwakọ̀ ní ọwọ́ left
Àmìọ̀rọ̀ Internet .bs
Àmìọ̀rọ̀o tẹlifóònù +1-242

Awon onibudo ibe tele ni awon Taino ti Arawaka, awon Bahama ni ibi ti Columbus koko gunle si ni Ile Aye Tuntun ni 1492. Botilejepe awon ara Spein ko se amunisin awon Bahama, won ko awon Lucaya abinibi ibe (eyi ni oruko ti awon Taino Bahama unpe ara won) lo si oko eru ni Hispaniola. Lati 1513 de 1650 enikankan ko gbe ori awon erekusu yi, ko to di pe awon olumunisin ara Britani lati Bermuda tedo si erekusu Eleuthera.


ItokaÀtúnṣe

  1. "1973: Bahamas' sun sets on British Empire" (HTML). BBC News. July 9, 1973. Retrieved 2009-05-01. 
  2. Population estimates for the Bahamas take into account the effects of excess mortality due to AIDS; this can result in lower life expectancy, higher infant mortality and death rates, lower population growth rates, and changes in the distribution of population by age and sex than would otherwise be expected.
  3. 3.0 3.1 3.2 3.3 "The Bahamas". International Monetary Fund. Retrieved 2009-04-22.