Moulay Abdallah (1694 – títí di ọjọ́ kẹwàá oṣù kọkànlá ọdún 1757) (Lárúbáwá: مولاي عبدالله بن إسماعيل‎) jẹ́ Sultan orílẹ̀ èdè Morocco lẹ́mẹfà láàrin 1729 sí 1757. Ó gun orí ìtẹ́ ní àwọn ọdún 1729–1734, 1736, 1740–1741, 1741–1742, 1743–1747 àti 1748–1757.[2] Òun ni ọmọ Sultan Ismail Ibn Sharif.

Moulay Abdallah
Reign 1729-1734
Predecessor Abu'l Abbas Ahmad II
Successor Ali
Reign 1736-1736, 1740-1741, 1741-1742, 1743-1747, 1748–1757
Predecessor Abdalmalik
Successor Sidi Mohammed III
Issue
Moulay Ahmed[1]
Sidi Mohammed III
Full name
Moulay Abdallah bin arbia bin Ismail as-Samin
House Alaouite dynasty
Father Ismail Ibn Sharif
Mother Khanatha bint Bakkar
Born 1694
Meknes, Morocco
Died 10 November 1757
Dar Debibagh
Burial Moulay Abdallah Mosque, Fez

Ìtàn ayé rẹ̀ àtúnṣe

Wọ́n bi ní ọdún 1694 sínú ìdílé Sultan Moulay Ismail àti ọkàn lára àwọn ìyàwó rẹ̀,Lalla Khanatha bint Bakkar. Ó gun orí ìtẹ́ ní òpò ìgbà, tí ó sì ń bá àwọn arákùnrin rẹ̀ jà. Òun ni ó kọ́kọ́ pe ara rẹ̀ ní sultan lẹ́yìn ikú òjìji tí ó pa arákùnrin rẹ̀, Sultan Moulay Ahmad ní ọjọ́ kàrún oṣù kẹta ọdún 1729.[3] Àwọn Abid, Udaya, àti gbogbo àwọn caid kóra jọ wọ́n sì fìmọ̀sọ̀kan láti pèé ní sultan Morocco.[3] Wọ́n rán àwọn ológun pẹ̀lú ẹṣin láti mu wá láti ibi tí ó ń gbé, Sijilmasa.

Lẹ́yìn ikú rẹ̀, wọ́n sín sí ibi ìsìnkú ti Moulay Abdallah Mosque tí ó kọ́ ní Fes el-Jdid.[4]

Àwọn Ìtọ́kasí àtúnṣe

  1. trans. from Arabic by Eugène Fumet, Ahmed ben Khâled Ennâsiri (in fr). Kitâb Elistiqsâ li-Akhbâri doual Elmâgrib Elaqsâ [" Le livre de la recherche approfondie des événements des dynasties de l'extrême Magrib "], vol. IX : Chronique de la dynastie alaouie au Maroc. Ernest Leroux. pp. 265. 
  2. Woodacre, E. (2013-12-18) (in en). Queenship in the Mediterranean: Negotiating the Role of the Queen in the Medieval and Early Modern Eras. Springer. pp. 229. ISBN 9781137362834. https://books.google.com/books?id=b0uvAgAAQBAJ&pg=PT229. 
  3. 3.0 3.1 trans. from Arabic by Eugène Fumet, Ahmed ben Khâled Ennâsiri (in fr). Kitâb Elistiqsâ li-Akhbâri doual Elmâgrib Elaqsâ [" Le livre de la recherche approfondie des événements des dynasties de l'extrême Magrib ", vol. IX : Chronique de la dynastie alaouie au Maroc]. Ernest Leroux. pp. 172–173. Archived from the original on 2021-10-04. https://web.archive.org/web/20211004001249/http://bnm.bnrm.ma:86/ClientBin/images/book704908/doc.pdf. Retrieved 2022-10-02. 
  4. Bressolette, Henri (2016). A la découverte de Fès. L'Harmattan. ISBN 978-2343090221.