Ismail Ibn Sharif
Moulay Ismail Ibn Sharif (Lárúbáwá: مولاي إسماعيل بن الشريف), tí a bí ní 1645 ní Sijilmassa tí ó sì fi ayé sílẹ̀ ní ọjọ́ kejìlélógún oṣù kẹta oṣù 1727 ní Meknes, jẹ́ Sultan Morocco láti ọdún 1672 sí 1727, gẹ́gẹ́ bi adarí kejì 'Alawi dynasty.[2] Òun ni ọmọkùnrin keje Moulay Sharif ó sì fi ìgbà kan jẹ́ Gómìnà àgbègbè Fez àti àríwá Morocco láti ọdún 1667 títí di ìgbà ikú arákùnrin rẹ̀, Sultan Moulay Rashid ní ọdún 1672. Wọ́n kéde rẹ̀ gẹ́gẹ́ sultan ní Fez, ṣùgbọ́n òun àti Moulay Ahmed ben Mehrez, ẹni kejì tí ó pe ara rẹ̀ ní Sultan jà fún ọ̀pọ̀ ọdún, Moulay Rashid padà fi ayé sílẹ̀ ní ọdún 1687. Moulay Ismail wà lórí oyè fún ọdún márùnléládọ́ta, èyí sì mú kí ó jẹ́ Sultan tí ó pẹ́ lórí oyè jù ní Morocco. Nígbà ayé rẹ̀, Moulay ní ìyàwó tí ó tó ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹta àti ọmọ tí ó tó ẹgbẹ̀rin.
Moulay Ismail Ibn Sharif مولاي إسماعيل بن الشريف | |
---|---|
2nd Ruler Alaouite dynasty
| |
Reign | 1672 – 1727 |
Coronation | 14 April 1672[1] |
Predecessor | Al-Rashid Ibn Sharif |
Successor | Abu'l Abbas Ahmad Ibn Ismail |
Reign | 1667 – 1672 |
Spouse | among others: Lalla Aisha Mubarka Khnata bent Bakkar Aouda Doukalia Nassira el-Salwi bint Mohammed el-Heyba Halima Al Sufyaniyah Lalla Umm al-Iz at-Taba |
Issue | |
Moulay Mohammed Zeydan Moulay Abdalmalik Moulay Ahmed Moulay Abdallah
| |
Full name | |
Moulay Ismail I Ibn Sharif Ibn Ali | |
Era dates | |
(17th–18th Centuries) | |
House | 'Alawi dynasty |
Father | Sharif ibn Ali |
Born | c. 1645 Sijilmassa, Morocco |
Died | 22 March 1727 Meknes, Morocco | (ọmọ ọdún 81–82)
Burial | March 1727 Mausoleum of Moulay Ismail, Meknes |
Religion | Sunni Islam |
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Morocco (Alaoui Dynasty)". www.usa-morocco.org. Archived from the original on 29 August 2005. Retrieved 10 April 2018. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ Abun-Nasr, J.M., A History of the Maghrib in the Islamic Period, page 230. Cambridge University Press, 1987