Abdullahi Adamu
Olóṣèlú Nàìjíríà, Gomina Ipinle Nasarawa
Abdullahi Adamu je omo orile-ede Naijiria ati gomina Ipinle Nasarawa tele. Ni Oṣu Kẹta ọdun 2022, Abdullahi Adamu jẹ aarẹ ẹgbẹ Congress of Progressives, ẹgbẹ to poju ni Naijiria. In March 2022, Abdullahi Adamu was appointed president of the Congress of Progressives party, the majority party in Nigeria.[1]
Abdullahi Adamu | |
---|---|
Gomina ti Ipinle Nasarawa | |
In office May 1999 – May 2007 | |
Asíwájú | Bala Mande |
Arọ́pò | Aliyu Doma |
Senator ti Orílè-èdè Nàìjíríà | |
Lọ́wọ́lọ́wọ́ | |
Ó gun orí àga May 2011 | |
Asíwájú | Abubakar Sodangi |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 23 Oṣù Keje 1946 Keffi, Nasarawa State, Naijiria |
Ọmọorílẹ̀-èdè | Naijiria |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | All Progressives Congress . (APC). |
Alma mater | University of Jos, Kaduna Polytechnic. |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
àtúnṣe- ↑ "POLITIQUE Le sénateur Abdullahi Adamu prend la tête du parti au pouvoir au Nigeria". Voa Afrique (in Èdè Faransé). 2022-03-27. Retrieved 2022-03-27. line feed character in
|title=
at position 10 (help)