Ìpínlẹ̀ Násáráwá
Ìpínlẹ̀ Násáráwá je ikan ninu àwon Ipinle 36 ni orile-ede Naijiria. Oluilu re ni Lafia.
Ìpínlẹ̀ Násáráwá Nasarawa State | |
---|---|
Nickname(s): | |
![]() Location of Nasarawa State in Nigeria | |
Country | ![]() |
Date created | 1 October 1996 |
Capital | Lafia |
Government | |
• Governor[1] | Umar Tanko al-Makura (APC) |
• Representatives | List |
Area | |
• Total | 27,117 km2 (10,470 sq mi) |
Population (2005) | |
• Total | 2,040,097 |
• Density | 75/km2 (190/sq mi) |
GDP (PPP) | |
• Year | 2007 |
• Total | $3.02 billion[2] |
• Per capita | $1,588[2] |
Time zone | UTC+01 (WAT) |
ISO 3166 code | NG-NA |
Website | nasarawastate.org |
Ítàn Ìdásílẹ̀Àtúnṣe
Ìpínlẹ̀ Nasarawa jẹ́ dídásílẹ̀ ní Ọjó kínní, osù kẹwàá, Ọdún 1996 nígbà ìsèjọba Abacha, tí wọ́n pín kúrò ní ìpínlẹ̀ Plateau odè oní.
Ijọba Ìbílẹ̀Àtúnṣe
Awọn ijọba íbílẹ̀ tí ó wà nì ìpínlẹ̀ Nasarawa jẹ́ mẹ́tàlá. (Afìhàn pẹ̀lú ònkà 2006 population[3]):
Nasarawa West Senatorial District | 716,802 |
---|---|
Karu | 205,477 |
Keffi | 92,664 |
Kokona | 109,749 |
Nasarawa | 189,835 |
Toto | 119,077 |
Nasarawa North Senatorial District | 335,453 |
Akwanga | 113,430 |
Eggon | 149,129 |
Wamba | 72,894 |
Nasarawa South Senatorial District | 811,020 |
Awe | 112,574 |
Doma | 139,607 |
Keana | 79,253 |
Lafia | 330,712 |
Obi | 148,874 |
Awọn èdèÀtúnṣe
Awọn orísìrísí èdè tí ó wà ní ìpínlè Nasarawa jẹ́ mókàndínlógbọ̀n.
Awọn èdè na wa nínú tábìlì yi ní nítítò Ijọba ìbílẹ̀ ìpínlè Nasarawa:[4]
LGA | Languages |
---|---|
Akwanga | Mada;Duhwa; Eggon; Fulani; Gwandara; Hausa; Mama; Ninzo; Numana; Nungu |
Awe | Hausa; Fulani; Gwandara; Eggon; Goemai; Lijili; Tiv; Wapan |
Doma | Alago; Tiv; Agatu; Fulani; Hausa; |
keffi | Hausa; Fulani; :madaGadeEggon;Gbagyi; Gwandara; Koro Wachi |
Karu | Gbagyi; Gwandara; Gade |
Keana | Alago; Gwandara Tiv; Fulani |
Kokona | Gwandara;mada Fulani; Hausa; Eggon |
Lafia | Bare-Bari; Hausa; Fulani; Ake;mada: Alago; Agatu; Eggon; Goemai; Gwandara; Kofyar; Lijili; Tiv; Wapan |
Nasarawa | Hausa; Fulani; Agatu; Alago; Basa; Egbura; Eloyi; Gade; Gbagyi; Gwandara; Eggon; Tiv |
Nasarawa-Eggon | Eggon; Mada; Nungu; Fulani; Hausa |
Obi | Alago; Hausa; Fulani; Eggon; Tiv |
Toto | Egbura Agatu; Eggon; Gade; Fulani; Hausa |
Wamba | Alumu-Tesu;ninzo:mada;rindre Bu; Eggon; Hasha; Fulani; Kantana; Nungu; Toro |
Ní ìpínlè Nasarawa, orísìrísí ẹ̀yà marundinlogbon ló wà. Àwọn tí wọn ma n sọ jù nì Miligi (Koro), Alago, Mada, Gwandara, Kunari, Hausa Fulani, Gwari, Rindre, Afo, Eggon and Ebina[5]
Ilé ẹ̀kọ́Àtúnṣe
Ìpínlẹ̀ Nasarawa ni awọn Ilé ẹ̀kọ́ bí:
- College of Education, Akwanga
- Federal Polytechnic Nasarawa
- College of Agriculture in Lafia
- Isa Mustapha Agwai I Polytechnic Lafia
- Nasarawa State University
- Mewar International University ní Masaka
- Bingham University at Karu
- Hill College of Education Gwanje Akwanga
- NACAP polytechnic Akwanga
- Command secondary school Lafia
- Command secondary school Rinze
- Vocational And Relevant technology board
Ìpínlè Nasarawa ní awọn ilé ẹ̀kọ́ alakobere àti girama bí the Federal Government Girls College, Kea.
Awon èèyàn jànkànjànkànÀtúnṣe
- Imaan Sulaiman-Ibrahim – Director-General of NAPTIP
- HRH Alhaji Abdullahi Amegwa Agbo - Osana of Keana
- HRH Alhaji Ahmadu Aliyu Ogah - Andoma of Doma
- Sen. Abdullahi Adamu - National Chairman, APC
- Suleiman Odapu-Public Relations Practitioner
ItokasiÀtúnṣe
- ↑ See List of Governors of Nasarawa State for a list of prior governors
- ↑ 2.0 2.1 "C-GIDD (Canback Global Income Distribution Database)". Canback Dangel. Retrieved 2008-08-20.
- ↑ 2006 Population Census, Federal Republic of Nigeria, National Bureau of Statistics. Archived from the original on 2009-03-25.
- ↑ "Nigeria". Ethnologue. https://www.ethnologue.com/country/NG.