Abdullahi Sule
Abdullahi Sule (a bi ni ọjọ kẹ́rìndínlọ́gbọ̀n, Oṣu kejila, ọdun 1959) jẹ oniṣowo ati olóṣèlú Naijiria ti o jẹ Gómìnà Ìpínlẹ̀ Nasarawa. Wọ́n yàn án gẹ́gẹ́ bí Gómìnà Ìpínlẹ̀ Nasarawa nínú ìdìbò Gómìnà ọdún 2019 lábẹ́ ètò ẹgbẹ́ òṣèlú All Progressive Congress (APC).[1][2][3]
Engineer Abdullahi Sule | |
---|---|
Gómìnà ìpínlẹ̀ Nasarawa | |
Bayaran Lafia | |
Asíwájú | Umaru Tanko Al-Makura |
Deputy | Dr Emmanuel Akabe |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 26 Oṣù Kejìlá 1959 Gudi Station, Akwanga, Nasarawa State, Nigeria |
Ọmọorílẹ̀-èdè | Nàìjíríà |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | All Progressive Congress |
(Àwọn) olólùfẹ́ | Hajiya Silifa, Hajiya Farida |
Àwọn òbí | Alhaji Sule(Father), Hajiya Hauwa Sule(Mother) |
Alma mater | Roman Catholic Mission (1968), Zang Commercial Secondary School (1974), Government Technical College, Bukuru (1977), Plateau State Polytechnic (1980), Indiana University (1980–1984). |
Occupation | Businessman, Engineer, Politician |
Ìgbésí ayé rẹ
àtúnṣeWọ́n bí Sule ní Gudi, Akwanga ní ìpínlẹ̀ Nasarawa ní ọjọ́ kẹrindinlogbon oṣù Kejìlá ọdún 1959.[4] Ni ọdún 1968, Ó kẹ́kọ́ ní ilé-ẹ̀kọ́ Roman Catholic Mission (RMC) tí ó wà ní Gudi Station, ti o sí parí ilé-ẹ̀kọ́ gírámà ní Zang Secondary School ní ọdún 1974.[4]
Òṣèlú
àtúnṣeNi ọjọ kẹwà oṣù kẹta ọdún 2019, wón kede Adullahi Sule gẹgẹ bi gómìnà Ipínlè Nasarawa ti wón dibo yan.[5][6][2]
Àwọn itọ́kasí
àtúnṣe- ↑ Muhammad, Ibraheem Hamza; Lafia (March 11, 2019). "INEC declares APC's Abdullahi Sule Governor-elect in Nasarawa". Daily Trust. Archived from the original on 23 March 2019. Retrieved 12 March 2019.
- ↑ 2.0 2.1 "INEC declares Abdullahi Sule winner Nasarawa guber poll". The Sun Nigeria. March 11, 2019. Retrieved 12 March 2019.
- ↑ "Govs not against direct primaries, says Gov Sule". Punch Newspapers. 2022-01-16. Retrieved 2022-03-06.
- ↑ 4.0 4.1 "APC 's Abdullahi Sule to battle PDP's Ombugadu in Nasarawa". News Agency of Nigeria (NAN). October 1, 2018. Archived from the original on 2 October 2018. Retrieved 12 March 2019.
- ↑ "Abdulahi Sule wins APC governorship primary in Nasarawa". The Express Tribune. October 1, 2018. Archived from the original on 2 October 2018. Retrieved 12 March 2019.
- ↑ "INEC Declares Abdullahi Sule Winner of Nasarawa Governorship Race – Channels Television". Retrieved 12 March 2019.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |