Abdullahi Umar Ganduje
Olóṣèlú
Abdullahi Umar Ganduje, OFR tí wọ́n bí ní Ọjọ́ kẹẹ̀ẹ́dọ́gbọ̀n oṣù Kejìlá ọdún 1945 (25 December 1945) jẹ́ olóṣèlú àti Gómìnà Ìpínlẹ̀ Kánò lọ́wọ́lọ́wọ́ láti ọdún 2015.[1] Kí ó tó di Gómìnà, òun ni igbákejì Gómìnà Ìpínlẹ̀ Kano, lọ́dún 1999 sí 2003 àti 2011 sí 2015.
Abdullahi Umar Ganduje | |
---|---|
Abdullahi Umar | |
Gómìnà Ìpínlẹ̀ Kánò | |
Lọ́wọ́lọ́wọ́ | |
Ó gun orí àga 29 May 2015 | |
Asíwájú | Rabiu Kwankwaso |
Deputy Governor of Ìpínlẹ̀ Kánò | |
In office 29 May 1999 – 29 May 2003 | |
Arọ́pò | Magaji Abdullahi |
In office 29 May 2011 – 29 May 2015 | |
Asíwájú | Abdullahi Tijjani Gwarzo |
Arọ́pò | Prof. Hafizu Abubakar |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 25 Oṣù Kejìlá 1949 Ganduje, Dawakin Tofa, Ìpínlẹ̀ Kánò |
Ọmọorílẹ̀-èdè | Nigerian |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | All Progressive Congress (APC) |
(Àwọn) olólùfẹ́ | Hafsat Umar |
Residence | Kano, Nàìjíríà |
Alma mater | Ahmadu Bello University Bayero University Kano University of Ibadan |
Occupation | Politician |
Profession | Administrator |
Website | ganduje.com.ng |
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ Nnochiri, Ikechukwu (2020-01-20). "Supreme Court upholds Ganduje's election, dismisses Yusuf's appeal". Vanguard News. Retrieved 2020-03-09.