Abel Adelakun Ayoko jẹ́ Asojú orílé èdè Nàìjíríà sí Austria and Slovakia.[1][2]

Abel Adelakun Ayoko
Abel Adelakun Ayoko
Ọjọ́ìbí14 February 1957
Ondo City
Orílẹ̀-èdèNigerian
Gbajúmọ̀ fúnAmbassador to Austria
SuccessorMaria Oyeyinka Laose

Ìgbé Aye

àtúnṣe

Ayoko (ibí 14 February 1957) jẹ́ ẹni tí ó gbà oyè master's degree ní International Law and Diplomacy. Ó ṣe ìsìn ní Nigerian Embassy ti Vienna gẹ́gẹ́ bí Senior Counsellor láti ọdún 1998 – 2002.

Ayoko jẹ́ ọmọ bíbí ìlú Ondo ní orílé èdè Nàìjíríà, ọ jáde fásitì University of Lagos ó sí gba oyè Masters láti fásitì kanna. Ayokoo tí ní ìyàwó pẹlú àwọn ọmọ ọkùnrin mẹrin. Ó ti wà ni iṣẹ́ àjèjì bí diplomat fún 32 years, àti pé ó tì sìn ní orísirísi orílé ède ni Ministry of Foreign Affairs. Ìsìn àkọkọ rẹ jẹ́ sí Lusaka ní ọdún 1987. Lati ibẹ̀ lọ ni woọ́n gbé lọ sí Angola ni ọdún 1989 tí ọmó wá níbè fún ọdún mẹrin. Iṣé rẹ nígbà náà ní kí ó kó àwọnọ̀dọ́ ènìyàn tí ó sùn láti lò sí ilé ìwé níNamibia ati South Africa. Awọn tí wọn mú wọn rán wọn pada sí Naijiria láti tún ni ṣé idanilẹkọ lórí bí a tí ń ṣe àtìlẹ́yìn fún àwọn ìlú nígbà tí òfin ìletò tí àwọn aláwọ̀ fúnfún. Nígbà náà ó jẹ Ọdọ òṣìṣẹ́ tí ó lówó nínú òṣèlú àti kíkọ òun tí ó ń ṣẹlẹ̀ láwùjọ Angola nígbà tí Ogun. Ṣùgbón wón pada gbé lọsí orílé èdè Nàìjíríà, leyin náà ní won gbé lọsí Austria ni orílé èdè Vienna gẹgẹ bí ọ̀dọ́ òṣìṣẹ́ láti ọdún 1998 sí 2002.

Ayoko gbà iṣẹ Asoju lọ́wọ Maria Oyeyinka Laose ẹnití ó ti ṣe iṣé Asoju fún ọdún méjì. Vivian Okeke gbé ẹrí kalẹ̀ gẹ́gẹ́ bí Asojú Nàìjíríà sí Ààrẹ Austria, Dr Alexander Van der Bellen, ní October 2017.[3]

Àwọn Ìtọ́kasi

àtúnṣe

Àdàkọ:Authority control