Maria Oyeyinka Laose je Asojú orílé-èdè Nàìjíríàn sí orílè-èdè Austria lati ọdún 2011 to 2013.[1][2] Laose tí ṣíṣe ní ilé iṣé àjèjì (Embassy) tí Nàìjíríà ni orílẹ̀-èdè Vienna. Laose sí jẹ́ ẹni Àríyànjiyàn tí àwọn ọmọ Naijiria tí wọn ń gbé Vienna ó ń ayé àti rí tàbí básọ̀rọ̀ [1]

Maria Oyeyinka Laose
Orílẹ̀-èdèNigeria
Iṣẹ́Ambassador to Austria

Wọn fi Abel Adelakun Ayoko rọ́pò Laose ní December ọdún 2013 eniti ọ ti ṣiṣẹ ni ìlé iṣé àjèjì Embassy.[3]

Àwọn ìtọ́kasí àtúnṣe

  1. 1.0 1.1 Uzoma Ahamefule :Foreign Affairs Visits:Temperature Of Nigerian Communities In Austria Rising Above Boiling Point, Uzoma Ahamefule, 2013, Daily Post, Retrieved February 2016
  2. "Nigerianische Botschafterin zu Gast in der Grazer Burg: Mögliche Kooperationen im Zentrum des Gesprächs". www.kommunikation.steiermark.at. Land Steiermark. January 27, 2012. Retrieved September 2, 2020. 
  3. Nigerians In Austria Welcomed Their New Ambassador Abel Adelakun Ayoko[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́], January 2014, Global Reporters, Retrieved 6 February 2016