Àwọn Obìnrin Akọ̀yà ìlú Abẹ́òkúta

(Àtúnjúwe láti Abeokuta Women's Revolt)

Àwọn obìnrin ajìjà-n-gbara tàbí Àwọn Obìnrin Akọ̀yà Ìlú Abẹ́òkúta ti ọdún 1940, jẹ́ ẹgbẹ́ ìgbìmọ̀ tó múnádóko, tó sì ní já fún ẹ̀tọ́ àwon obìnrin ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.

Àwọn egbé Obìnrin Abẹ́òkúta fi ẹ̀hónú wọn hàn sí ètó ìṣèjọba amúnisìn àwọn Gẹ̀ẹ́sì, ẹgbẹ́ yí lòdì sí kí àwọn obìnrin má a san owó-orí ní Ìlẹ̀ Nàìjíríà.

Àwọn obìnrin Ìlú Abẹ́òkúta yìí gbàgbọ́ pé lábẹ́ ìjọba amúnisìn, àwon ètó ọrọ̀ aje wọn kò tẹ̀síwájú, lákòókò tí owó-orí tí ìjọba ń gbà tún pọ̀ sí i. [1]

Bákań nàa, àwọn ẹgbẹ́ obìnrin yìí sọ wí pé kò yẹ rárá kí wọ́n má a san owó-orí lọ́tọ̀, ní wọ̀n ìgbà tí àwọn ọkọ wọn ti ní san-án. Síwájú sí i, ó yẹ kí àwọn obìnrin náà lẹ́tọ̀ọ́ láti ṣe aṣojú ní ìṣèjọba agbègbè.

Gẹ́gẹ́bí èròńgbà wọn, ìjọba gba àbádòfin kí wọ́n fún àwọn obìnrin láyè láti kópa. Wọ́n sì fún àwọn mẹ́rin láyè láti ṣe aṣojú ìjọba ní agbegbe. Òpin sí débá kí obìnrin má a san owó-óri ní Ìlú ẹ̀gbá áti ilẹ́ Nàìjííríà.

Ìpàtẹ ọjà èso obì

Ìlú Abẹ́òkúta jẹ́ Ìlú tí àwọn ẹ̀yà Yorùbá ń gbé, tí ó sì wà ní gúúsù ìwọ̀-oòrùn Nàìjíríà.

Ní ọdún 1830 ni wọ́n dá Ìlú Abẹ́òkúta sílẹ̀, tí àwọn Ẹ̀gbá àti Òwu jẹ́ olùgbé àkọ́kọ́ lórí ilẹ̀ náà.

Ní ọdún 1850, tí ètó ìjọba amúnisìn ti Ilu Gẹ̀ẹ́sì bẹ̀rẹ̀ láti fa ìṣàkóso rẹ̀ sí Ìlú Abẹ́òkúta àti àwọn àdéhùn pẹ̀lú àwon omo bíbí Ègbá. Ìwé Àdéhùn yìí ló fàyè gba àwọn gbogbo Ìlú Ègbá lápapọ́ ki ìbáṣepọ tó dán mọ́rán le wà lórí ètò ọrọ̀ ajé wọn láti ileto kan si miran ati ibodè ikan dè miíràn. Kí ààlà ati ètò ọrọ̀ ajé wọn pẹ̀lú Ìlú Èkó fún ìgbáradì ètò òmìnìra túnbọ́ rọrùn láti leè bọ́ lọ́wọ́ ìṣèjọba amúnisìn ilẹ̀ Gẹ̀ẹ́sì.

[1]

Àdéhùn yìí ti fún àwọn èèyàn Ègbá ní òmìnìra tó ní órí ètòlorọ̀ eto-ọrọ tiwọn, ṣùgbọ́n ní ìkẹhìn, ìjọba Gẹ̀ẹ́sì wá ọ̀nà láti làjà ní ètò àdáṣe lẹ́hìn ìdààmú olóṣèlú kan ní ọdún 1897. Ìjọba Gẹ̀ẹ́sì bẹ̀ẹ̀rẹ̀ àtúntò ètò òṣèlú

Ìlú náà, eléyìí ló ṣokùnfà dídá ijọba Egba United (EUG) sílẹ̀. Ṣáájú sì ètò tuntun, àwọn ìgbìmọ̀ agbègbè ní àdéhùn pẹ̀lú pé ó kéré jù, obìnrin kan gbọ́dọ̀ wà lára àwọn aṣoju. EUG, lára àṣà wọn tẹ́lẹ̀rí, Ọkùnrin nìkan ni wọ́n fi ń ṣe aṣojú kí iṣẹ́ ìdàgbàsòkè àti ètò amáyédẹrùn bẹ̀rè ní Ìlú Abéòkúta. EUG ṣe àwọn iṣẹ́ àkànṣe àti ìdàgbàsókè ohun amáyédẹrùn, bí i ètò ọrọ́-ajé, ṣíṣe àwọn ojú ọ̀nà, àti dókòwò pẹ̀lù ilẹ̀ Òkèèrè, nípa ká fi àwọn n

kaní iiòkó,o, e-pupa, obì,aà ati aṣàdìrẹ.n. íi ipariọdúnn 1800s,Ìlú Aéòkúuta tidi Ìlú ńlá tó lókìkí tó sì gbàjúmọ̀ lórí ètò ọrọ̀ ajé láàrín àwọn Ìlú míràn íio àìjíríàaàati éewọ́n dádúró bí Ìlú tó ti gba òmìnìiratirẹ̀.

Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. 1.0 1.1 Byfield, Judith A. "Taxation, Women, and the Colonial State: Egba Women's Revolt." Meridians: Feminism, Race, Transnationalism, 3.2 (2003): 250–77. Web. 4 March 2013.