Acanthotheelia
Acanthotheelia jẹ́ ìdílé kòkúmbà òkún tí a kò rí mọ́ ṣùgbọ́n tí a ti rí tẹ́lẹ́ ni Poland ní ìgbà Triassic.[1] Àwọn ẹ́yà tí ó wà nínú rẹ̀ ni Acanthotheelia spinosa, Acanthotheelia spiniperjorata, àti Acanthotheelia anisica.
Acanthotheelia | |
---|---|
Ìṣètò onísáyẹ́nsì | |
Ìjọba: | |
Ará: | |
Ẹgbẹ́: | |
Ìtò: | |
Ìdílé: | |
Ìbátan: | Acanthotheelia Frizzell & Exline, 1955
|
Type species | |
Acanthotheelia spinosa Frizzell & Exline, 1955
|
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ Krystyna Zawidzka (1974). "Triassic Holothurian Sclerites from Tatra Mountains" (PDF). Acta Palaeontologica Polonica 16 (4): 429–450. http://app.pan.pl/archive/published/app16/app16-429.pdf.